ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 5:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Jésù sọ fún un pé: “Dìde! Gbé ẹní* rẹ, kí o sì máa rìn.”+ 9 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ara ọkùnrin náà yá, ó gbé ẹní* rẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í rìn.

      Ọjọ́ Sábáàtì ni.

  • Ìṣe 9:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Pétérù sọ fún un pé: “Énéà, Jésù Kristi mú ọ lára dá.+ Dìde, kí o sì tẹ́ ibùsùn rẹ.”+ Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó dìde.

  • Ìṣe 14:8-10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní Lísírà, ọkùnrin kan wà ní ìjókòó tí ẹsẹ̀ rẹ̀ rọ. Àtìgbà tí wọ́n ti bí i ló ti yarọ, kò sì rìn rí. 9 Ọkùnrin yìí ń fetí sí Pọ́ọ̀lù bó ṣe ń sọ̀rọ̀. Bí Pọ́ọ̀lù ṣe tẹjú mọ́ ọn, tó sì rí i pé ó ní ìgbàgbọ́ pé òun lè rí ìwòsàn,+ 10 ó gbóhùn sókè pé: “Dìde lórí ẹsẹ̀ rẹ.” Ọkùnrin náà fò sókè, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í rìn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́