Àìsáyà 52:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi+ máa fi ìjìnlẹ̀ òye hùwà. A máa gbé e ga,A máa gbé e lékè, a sì máa gbé e ga gidigidi.+ Àìsáyà 53:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn. Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodoMáa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+
13 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi+ máa fi ìjìnlẹ̀ òye hùwà. A máa gbé e ga,A máa gbé e lékè, a sì máa gbé e ga gidigidi.+
11 Torí ìrora* rẹ̀, ó máa rí i, ó sì máa tẹ́ ẹ lọ́rùn. Nípasẹ̀ ìmọ̀ rẹ̀, ìránṣẹ́ mi+ tó jẹ́ olódodoMáa mú kí a ka ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn sí olódodo,+Ó sì máa ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+