Hébérù 10:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Torí tí a bá mọ̀ọ́mọ̀ sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà lẹ́yìn tí a ti gba ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́,+ kò tún sí ẹbọ kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ mọ́,+ 27 àfi ká máa fi ìbẹ̀rù retí ìdájọ́ àti ìbínú tó le, tó sì máa jó àwọn tó ń ṣàtakò run.+
26 Torí tí a bá mọ̀ọ́mọ̀ sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà lẹ́yìn tí a ti gba ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́,+ kò tún sí ẹbọ kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ mọ́,+ 27 àfi ká máa fi ìbẹ̀rù retí ìdájọ́ àti ìbínú tó le, tó sì máa jó àwọn tó ń ṣàtakò run.+