Fílípì 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 mò ń sapá kí ọwọ́ mi lè tẹ èrè+ ìpè+ Ọlọ́run sí òkè nípasẹ̀ Kristi Jésù. 1 Tẹsalóníkà 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 kí ẹ lè máa rìn lọ́nà tó yẹ Ọlọ́run,+ ẹni tó ń pè yín sí Ìjọba+ àti ògo rẹ̀.+ Hébérù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, ẹ̀yin ará tí ẹ jẹ́ mímọ́, ẹ̀yin tí ẹ ní ìpè* ti ọ̀run,+ ẹ ronú nípa àpọ́sítélì àti àlùfáà àgbà tí a gbà,* ìyẹn Jésù.+
3 Torí náà, ẹ̀yin ará tí ẹ jẹ́ mímọ́, ẹ̀yin tí ẹ ní ìpè* ti ọ̀run,+ ẹ ronú nípa àpọ́sítélì àti àlùfáà àgbà tí a gbà,* ìyẹn Jésù.+