11 Ó gba àmì kan,+ ìyẹn, ìdádọ̀dọ́,* gẹ́gẹ́ bí èdìdì* òdodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ tó ní nígbà tó ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́,* kí ó lè jẹ́ baba gbogbo àwọn tó ní ìgbàgbọ́+ nígbà tí wọ́n ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́, kí a lè kà wọ́n sí olódodo;
9 kí ó sì hàn pé mo wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, kì í ṣe nítorí òdodo tèmi nínú pípa Òfin mọ́, àmọ́ ó jẹ́ nítorí òdodo tó wá nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ + nínú Kristi,+ òdodo tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, tó sì dá lórí ìgbàgbọ́.+