Àìsáyà 53:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Ta ló ti nígbàgbọ́ nínú ohun tó gbọ́ lọ́dọ̀ wa?*+ Ní ti apá Jèhófà,+ ta la ti fi hàn?+ Jòhánù 12:37, 38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ó ti ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì níwájú wọn, wọn ò ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀, 38 kí ọ̀rọ̀ wòlíì Àìsáyà lè ṣẹ, ẹni tó sọ pé: “Jèhófà,* ta ló ti nígbàgbọ́ nínú ohun tó gbọ́ lọ́dọ̀ wa?*+ Ní ti apá Jèhófà,* ta la ti ṣí i payá fún?”+
37 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ó ti ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì níwájú wọn, wọn ò ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀, 38 kí ọ̀rọ̀ wòlíì Àìsáyà lè ṣẹ, ẹni tó sọ pé: “Jèhófà,* ta ló ti nígbàgbọ́ nínú ohun tó gbọ́ lọ́dọ̀ wa?*+ Ní ti apá Jèhófà,* ta la ti ṣí i payá fún?”+