-
Ìṣe 2:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àmọ́, Pétérù dìde dúró pẹ̀lú àwọn Mọ́kànlá náà,+ ó gbóhùn sókè, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin èèyàn Jùdíà àti gbogbo ẹ̀yin tó ń gbé ní Jerúsálẹ́mù, ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yìí yé yín, kí ẹ sì fara balẹ̀ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi.
-