ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 4:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nítorí náà, ẹ má ṣèdájọ́+ ohunkóhun ṣáájú àkókò tó yẹ, títí Olúwa yóò fi dé. Yóò mú àwọn ohun ìkọ̀kọ̀ inú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀, á sì jẹ́ kí a mọ èrò ọkàn àwọn èèyàn, lẹ́yìn náà, kálukú á gba ìyìn rẹ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.+

  • 1 Kọ́ríńtì 5:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 kí ẹ fi irú ẹni bẹ́ẹ̀ lé Sátánì lọ́wọ́+ kí agbára ẹ̀ṣẹ̀ náà lè pa run, kí ipò tẹ̀mí ìjọ lè wà láìyingin ní ọjọ́ Olúwa.+

  • Ìfihàn 1:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Mo wà ní ọjọ́ Olúwa nípasẹ̀ ìmísí, mo sì gbọ́ ohùn kan lẹ́yìn mi tó rinlẹ̀ bíi ti kàkàkí,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́