Ẹ́kísódù 31:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbàrà tó bá a sọ̀rọ̀ tán lórí Òkè Sínáì, ó fún Mósè ní wàláà Ẹ̀rí méjì,+ àwọn wàláà òkúta tí ìka Ọlọ́run+ kọ̀wé sí. Ẹ́kísódù 34:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Kí ìwọ fúnra rẹ gbẹ́ wàláà òkúta méjì, irú ti àkọ́kọ́,+ màá sì kọ àwọn ọ̀rọ̀ tó wà lórí àwọn wàláà àkọ́kọ́+ tí o fọ́ túútúú+ sára rẹ̀.
18 Gbàrà tó bá a sọ̀rọ̀ tán lórí Òkè Sínáì, ó fún Mósè ní wàláà Ẹ̀rí méjì,+ àwọn wàláà òkúta tí ìka Ọlọ́run+ kọ̀wé sí.
34 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Kí ìwọ fúnra rẹ gbẹ́ wàláà òkúta méjì, irú ti àkọ́kọ́,+ màá sì kọ àwọn ọ̀rọ̀ tó wà lórí àwọn wàláà àkọ́kọ́+ tí o fọ́ túútúú+ sára rẹ̀.