Sáàmù 23:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí mo tilẹ̀ ń rìn nínú àfonífojì tó ṣókùnkùn biribiri,+Mi ò bẹ̀rù ewukéwu,+Nítorí o wà pẹ̀lú mi;+Ọ̀gọ* rẹ àti ọ̀pá rẹ ń fi mí lọ́kàn balẹ̀.* 2 Kọ́ríńtì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ Ọlọ́run tó ń tu àwọn tí ìrẹ̀wẹ̀sì bá nínú,+ ti tù wá nínú bí Títù ṣe wà pẹ̀lú wa;
4 Bí mo tilẹ̀ ń rìn nínú àfonífojì tó ṣókùnkùn biribiri,+Mi ò bẹ̀rù ewukéwu,+Nítorí o wà pẹ̀lú mi;+Ọ̀gọ* rẹ àti ọ̀pá rẹ ń fi mí lọ́kàn balẹ̀.*