ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 6:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Bí a ṣe wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀ lọ́nà tó gbà kú,+ ó dájú pé a ó tún lè wà níṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀ lọ́nà tó gbà jíǹde.+

  • Róòmù 8:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ àwa fúnra wa pẹ̀lú tí a ní àkọ́so, ìyẹn, ẹ̀mí náà, bẹ́ẹ̀ ni, àwa fúnra wa ń kérora nínú ara wa,+ bí a ṣe ń dúró de ìsọdọmọ+ lójú méjèèjì, ìyẹn ìtúsílẹ̀ kúrò nínú ara wa nípasẹ̀ ìràpadà.

  • 1 Kọ́ríńtì 15:48, 49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Bí ẹni tí a fi erùpẹ̀ dá ṣe rí ni àwọn tí a fi erùpẹ̀ dá náà rí; bí ẹni ti ọ̀run ṣe rí ni àwọn tí wọ́n jẹ́ ti ọ̀run náà rí.+ 49 Bí a ṣe gbé àwòrán ẹni tí a fi erùpẹ̀ dá wọ̀,+ bẹ́ẹ̀ náà ni a máa gbé àwòrán ẹni ti ọ̀run wọ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́