Ìṣe 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ Olúwa sọ fún un pé: “Lọ! nítorí ohun èlò tí a ti yàn ni ọkùnrin yìí jẹ́ fún mi+ láti mú orúkọ mi lọ sọ́dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè+ àti àwọn ọba+ àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Róòmù 11:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ní báyìí, ẹ̀yin tí ẹ wá láti àwọn orílẹ̀-èdè ni mo fẹ́ bá sọ̀rọ̀. Bí mo ṣe jẹ́ àpọ́sítélì fún àwọn orílẹ̀-èdè,+ mo ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ mi lógo*+
15 Àmọ́ Olúwa sọ fún un pé: “Lọ! nítorí ohun èlò tí a ti yàn ni ọkùnrin yìí jẹ́ fún mi+ láti mú orúkọ mi lọ sọ́dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè+ àti àwọn ọba+ àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
13 Ní báyìí, ẹ̀yin tí ẹ wá láti àwọn orílẹ̀-èdè ni mo fẹ́ bá sọ̀rọ̀. Bí mo ṣe jẹ́ àpọ́sítélì fún àwọn orílẹ̀-èdè,+ mo ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ mi lógo*+