15 Àmọ́ Olúwa sọ fún un pé: “Lọ! nítorí ohun èlò tí a ti yàn ni ọkùnrin yìí jẹ́ fún mi+ láti mú orúkọ mi lọ sọ́dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè+ àti àwọn ọba+ àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
15 Àmọ́ nígbà tí Ọlọ́run, ẹni tó yọ mí nínú ikùn ìyá mi, tó sì pè mí nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀,+ rí i pé ó dára 16 láti ṣí Ọmọ rẹ̀ payá nípasẹ̀ mi, kí n lè kéde ìhìn rere nípa rẹ̀ fún àwọn orílẹ̀-èdè,+ mi ò lọ fọ̀rọ̀ lọ ẹnikẹ́ni* lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀;
8 Èmi, tí mo kéré ju ẹni tó kéré jù lọ nínú gbogbo ẹni mímọ́,+ la fún ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí yìí,+ kí n lè kéde ìhìn rere nípa ọrọ̀ Kristi tí kò ṣeé díwọ̀n fún àwọn orílẹ̀-èdè,