ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 8:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Nígbà náà, tí a bá jẹ́ ọmọ, ajogún ni wá pẹ̀lú, lóòótọ́ a jẹ́ ajogún Ọlọ́run, àmọ́ a jẹ́ ajùmọ̀jogún+ pẹ̀lú Kristi, kìkì tí a bá jọ jìyà,+ kí a lè ṣe wá lógo pẹ̀lú rẹ̀.+

  • Éfésù 3:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ní àwọn ìran ìṣáájú, a kò fi àṣírí yìí han àwọn ọmọ èèyàn bí a ṣe fi han àwọn wòlíì àti àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ mímọ́ nípasẹ̀ ẹ̀mí lásìkò yìí,+ 6 ìyẹn ni pé, nínú Kristi Jésù àti nípasẹ̀ ìhìn rere, kí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè lè di ajùmọ̀jogún, kí a jọ jẹ́ ẹ̀yà ara kan náà,+ kí a sì jọ pín nínú ìlérí náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́