1 Pétérù 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ti ìgbàlà yìí, àwọn wòlíì tí wọ́n sọ tẹ́lẹ̀ nípa inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tó jẹ́ tiyín, fara balẹ̀ wádìí, wọ́n sì fẹ̀sọ̀ wá a.+ 1 Pétérù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 A ṣí i payá fún wọn pé wọ́n ń ṣe òjíṣẹ́, kì í ṣe fún ara wọn, àmọ́ fún yín, nípa àwọn ohun tí àwọn tó kéde ìhìn rere fún yín ti wá sọ fún yín nípasẹ̀ ẹ̀mí mímọ́ tó wá láti ọ̀run.+ Ó wu àwọn áńgẹ́lì gan-an pé kí wọ́n wo àwọn nǹkan yìí fínnífínní.
10 Ní ti ìgbàlà yìí, àwọn wòlíì tí wọ́n sọ tẹ́lẹ̀ nípa inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tó jẹ́ tiyín, fara balẹ̀ wádìí, wọ́n sì fẹ̀sọ̀ wá a.+
12 A ṣí i payá fún wọn pé wọ́n ń ṣe òjíṣẹ́, kì í ṣe fún ara wọn, àmọ́ fún yín, nípa àwọn ohun tí àwọn tó kéde ìhìn rere fún yín ti wá sọ fún yín nípasẹ̀ ẹ̀mí mímọ́ tó wá láti ọ̀run.+ Ó wu àwọn áńgẹ́lì gan-an pé kí wọ́n wo àwọn nǹkan yìí fínnífínní.