ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 5:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “Ẹ̀yin ni iyọ̀+ ayé, àmọ́ tí iyọ̀ ò bá lágbára mọ́, báwo ló ṣe máa pa dà ní adùn rẹ̀? Kò ṣeé lò fún ohunkóhun mọ́, àfi ká dà á síta,+ kí àwọn èèyàn tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀.

  • Máàkù 9:50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 Iyọ̀ dáa, àmọ́ tí iyọ̀ bá sọ adùn rẹ̀ nù pẹ́nrẹ́n, kí lẹ máa fi mú òun fúnra rẹ̀ dùn?+ Ẹ ní iyọ̀ nínú ara yín,+ kí ẹ sì jẹ́ kí àlàáfíà wà láàárín yín.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́