Sáàmù 37:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Láìpẹ́, àwọn ẹni burúkú ò ní sí mọ́;+ Wàá wo ibi tí wọ́n wà tẹ́lẹ̀,Wọn ò ní sí níbẹ̀.+ Jeremáyà 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Wọ́n sì ń wo àárẹ̀* ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi sàn láàbọ̀,* wọ́n ń sọ pé,“Àlàáfíà wà! Àlàáfíà wà!” Nígbà tí kò sí àlàáfíà.+
11 Wọ́n sì ń wo àárẹ̀* ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi sàn láàbọ̀,* wọ́n ń sọ pé,“Àlàáfíà wà! Àlàáfíà wà!” Nígbà tí kò sí àlàáfíà.+