Jóòbù 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 ó wá sọ pé: “Ìhòòhò ni mo jáde látinú ikùn ìyá mi,Ìhòòhò ni màá sì pa dà.+ Jèhófà ti fúnni,+ Jèhófà sì ti gbà á. Ká máa yin orúkọ Jèhófà títí lọ.” Sáàmù 49:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Má bẹ̀rù nítorí pé ẹnì kan di ọlọ́rọ̀,Nítorí pé ògo ilé rẹ̀ ń pọ̀ sí i,17 Nítorí tí ó bá kú, kò lè mú ohunkóhun lọ;+Ògo rẹ̀ kò ní bá a sọ̀ kalẹ̀ lọ.+
21 ó wá sọ pé: “Ìhòòhò ni mo jáde látinú ikùn ìyá mi,Ìhòòhò ni màá sì pa dà.+ Jèhófà ti fúnni,+ Jèhófà sì ti gbà á. Ká máa yin orúkọ Jèhófà títí lọ.”
16 Má bẹ̀rù nítorí pé ẹnì kan di ọlọ́rọ̀,Nítorí pé ògo ilé rẹ̀ ń pọ̀ sí i,17 Nítorí tí ó bá kú, kò lè mú ohunkóhun lọ;+Ògo rẹ̀ kò ní bá a sọ̀ kalẹ̀ lọ.+