34 kí àwọn obìnrin máa dákẹ́ nínú ìjọ, nítorí a kò gbà wọ́n láyè láti sọ̀rọ̀.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, kí wọ́n wà ní ìtẹríba,+ gẹ́gẹ́ bí Òfin ṣe sọ. 35 Tí wọ́n bá fẹ́ mọ nǹkan kan, kí wọ́n béèrè lọ́wọ́ ọkọ wọn nílé, nítorí ohun ìtìjú ni kí obìnrin máa sọ̀rọ̀ nínú ìjọ.