Sáàmù 110:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà ti búra, kò sì ní pèrò dà,* ó ní: “Ìwọ jẹ́ àlùfáà títí láé+Ní ọ̀nà ti Melikisédékì!”+