Lúùkù 1:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 ó máa jẹ Ọba lórí ilé Jékọ́bù títí láé, Ìjọba rẹ̀ ò sì ní lópin.”+ Hébérù 7:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Èyí wá túbọ̀ ṣe kedere nígbà tí àlùfáà+ míì tó dà bíi Melikisédékì+ dìde, 16 ẹni tó jẹ́ pé kì í ṣe ohun tí òfin sọ nípa ibi tí èèyàn ti ṣẹ̀ wá ló mú kó rí bẹ́ẹ̀, àmọ́ ó jẹ́ nípasẹ̀ agbára ìwàláàyè tí kò ṣeé pa run.+
15 Èyí wá túbọ̀ ṣe kedere nígbà tí àlùfáà+ míì tó dà bíi Melikisédékì+ dìde, 16 ẹni tó jẹ́ pé kì í ṣe ohun tí òfin sọ nípa ibi tí èèyàn ti ṣẹ̀ wá ló mú kó rí bẹ́ẹ̀, àmọ́ ó jẹ́ nípasẹ̀ agbára ìwàláàyè tí kò ṣeé pa run.+