Léfítíkù 16:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kó tún fi ìka rẹ̀ wọ́n lára ẹ̀jẹ̀ náà sára pẹpẹ lẹ́ẹ̀méje, kó lè wẹ̀ ẹ́ mọ́, kó sì sọ ọ́ di mímọ́ kúrò nínú ìwà àìmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. 20 “Tó bá ti ṣe ètùtù+ fún ibi mímọ́ náà tán, pẹ̀lú àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ,+ kó tún mú ààyè ewúrẹ́+ náà wá.
19 Kó tún fi ìka rẹ̀ wọ́n lára ẹ̀jẹ̀ náà sára pẹpẹ lẹ́ẹ̀méje, kó lè wẹ̀ ẹ́ mọ́, kó sì sọ ọ́ di mímọ́ kúrò nínú ìwà àìmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. 20 “Tó bá ti ṣe ètùtù+ fún ibi mímọ́ náà tán, pẹ̀lú àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ,+ kó tún mú ààyè ewúrẹ́+ náà wá.