Hébérù 8:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn èèyàn yìí ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ bí àpẹẹrẹ àti òjìji+ àwọn nǹkan ti ọ̀run;+ bí a ṣe pàṣẹ fún Mósè láti ọ̀run, nígbà tó fẹ́ kọ́ àgọ́ náà pé: Torí Ó sọ pé: “Rí i pé o ṣe gbogbo nǹkan bí ohun tí mo fi hàn ọ́ lórí òkè.”+
5 Àwọn èèyàn yìí ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ bí àpẹẹrẹ àti òjìji+ àwọn nǹkan ti ọ̀run;+ bí a ṣe pàṣẹ fún Mósè láti ọ̀run, nígbà tó fẹ́ kọ́ àgọ́ náà pé: Torí Ó sọ pé: “Rí i pé o ṣe gbogbo nǹkan bí ohun tí mo fi hàn ọ́ lórí òkè.”+