-
Máàkù 6:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 wọ́n lé ẹ̀mí èṣù púpọ̀ jáde,+ wọ́n fi òróró pa àwọn aláìsàn lára, wọ́n sì wò wọ́n sàn.
-
-
Lúùkù 10:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Torí náà, ó sún mọ́ ọn, ó di àwọn ọgbẹ́ rẹ̀, ó sì da òróró àti wáìnì sí i. Ó wá gbé e sórí ẹran rẹ̀, ó gbé e lọ sí ilé ìgbàlejò kan, ó sì tọ́jú rẹ̀.
-