Éfésù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra ogun+ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ lè dúró gbọn-in láti dojú kọ àwọn àrékérekè* Èṣù; Jémíìsì 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí náà, ẹ fi ara yín sábẹ́ Ọlọ́run;+ àmọ́ ẹ dojú ìjà kọ Èṣù,+ ó sì máa sá kúrò lọ́dọ̀ yín.+
11 Ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra ogun+ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ lè dúró gbọn-in láti dojú kọ àwọn àrékérekè* Èṣù;