Ẹ́kísódù 34:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà ń kọjá níwájú rẹ̀, ó sì ń kéde pé: “Jèhófà, Jèhófà, Ọlọ́run aláàánú,+ tó ń gba tẹni rò,*+ tí kì í tètè bínú,+ tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀*+ àti òtítọ́*+ rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi, Míkà 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+ 1 Jòhánù 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 A nífẹ̀ẹ́ torí òun ló kọ́kọ́ nífẹ̀ẹ́ wa.+
6 Jèhófà ń kọjá níwájú rẹ̀, ó sì ń kéde pé: “Jèhófà, Jèhófà, Ọlọ́run aláàánú,+ tó ń gba tẹni rò,*+ tí kì í tètè bínú,+ tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀*+ àti òtítọ́*+ rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi,
18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+