Mátíù 24:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Torí orílẹ̀-èdè máa dìde sí orílẹ̀-èdè àti ìjọba sí ìjọba,+ àìtó oúnjẹ+ àti ìmìtìtì ilẹ̀ sì máa wà láti ibì kan dé ibòmíì.+ Lúùkù 21:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó wá sọ fún wọn pé: “Orílẹ̀-èdè máa dìde sí orílẹ̀-èdè+ àti ìjọba sí ìjọba.+
7 “Torí orílẹ̀-èdè máa dìde sí orílẹ̀-èdè àti ìjọba sí ìjọba,+ àìtó oúnjẹ+ àti ìmìtìtì ilẹ̀ sì máa wà láti ibì kan dé ibòmíì.+