Ìfihàn 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Tíátírà+ pé: Ohun tí Ọmọ Ọlọ́run sọ nìyí, ẹni tí ojú rẹ̀ dà bí ọwọ́ iná tó ń jó fòfò,+ tí ẹsẹ̀ rẹ̀ sì dà bíi bàbà tó dáa gan-an:+
18 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Tíátírà+ pé: Ohun tí Ọmọ Ọlọ́run sọ nìyí, ẹni tí ojú rẹ̀ dà bí ọwọ́ iná tó ń jó fòfò,+ tí ẹsẹ̀ rẹ̀ sì dà bíi bàbà tó dáa gan-an:+