Ìṣe 26:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 pé Kristi máa jìyà+ àti pé bó ṣe jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí a máa jí dìde kúrò nínú ikú,+ ó máa kéde ìmọ́lẹ̀ fún àwọn èèyàn yìí àti fún àwọn orílẹ̀-èdè.”+ Kólósè 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 òun sì ni orí fún ara, ìyẹn ìjọ.+ Òun ni ìbẹ̀rẹ̀, àkọ́bí nínú àwọn òkú,+ kí ó lè di ẹni àkọ́kọ́ nínú ohun gbogbo; Ìfihàn 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 àti látọ̀dọ̀ Jésù Kristi, “Ẹlẹ́rìí Olóòótọ́,”+ “àkọ́bí nínú àwọn òkú,”+ àti “Alákòóso àwọn ọba ayé.”+ Ẹni tó nífẹ̀ẹ́ wa,+ tó fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ dá wa sílẹ̀ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+—
23 pé Kristi máa jìyà+ àti pé bó ṣe jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí a máa jí dìde kúrò nínú ikú,+ ó máa kéde ìmọ́lẹ̀ fún àwọn èèyàn yìí àti fún àwọn orílẹ̀-èdè.”+
18 òun sì ni orí fún ara, ìyẹn ìjọ.+ Òun ni ìbẹ̀rẹ̀, àkọ́bí nínú àwọn òkú,+ kí ó lè di ẹni àkọ́kọ́ nínú ohun gbogbo;
5 àti látọ̀dọ̀ Jésù Kristi, “Ẹlẹ́rìí Olóòótọ́,”+ “àkọ́bí nínú àwọn òkú,”+ àti “Alákòóso àwọn ọba ayé.”+ Ẹni tó nífẹ̀ẹ́ wa,+ tó fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ dá wa sílẹ̀ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+—