ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìfihàn 13:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 A gbà á láyè pé kó fún ère ẹranko náà ní èémí,* kí ère ẹranko náà lè sọ̀rọ̀, kó sì mú kí wọ́n pa gbogbo àwọn tó kọ̀ láti jọ́sìn ère ẹranko náà.

  • Ìfihàn 19:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 A sì mú ẹranko náà pẹ̀lú wòlíì èké+ tó ṣe àwọn iṣẹ́ àmì níwájú rẹ̀, èyí tó fi ṣi àwọn tó gba àmì ẹranko náà+ lọ́nà àti àwọn tó jọ́sìn ère rẹ̀.+ A ju àwọn méjèèjì láàyè sínú adágún iná tó ń jó, tí a fi imí ọjọ́ sí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́