Ìfihàn 17:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọ̀kan lára àwọn áńgẹ́lì méje tó ní abọ́ méje+ náà wá, ó sì sọ fún mi pé: “Wá, màá fi ìdájọ́ aṣẹ́wó ńlá tó jókòó lórí omi púpọ̀ hàn ọ́,+ 2 ẹni tí àwọn ọba ayé bá ṣe ìṣekúṣe,*+ tí a sì mú kí àwọn tó ń gbé ayé mu wáìnì ìṣekúṣe* rẹ̀ ní àmupara.”+
17 Ọ̀kan lára àwọn áńgẹ́lì méje tó ní abọ́ méje+ náà wá, ó sì sọ fún mi pé: “Wá, màá fi ìdájọ́ aṣẹ́wó ńlá tó jókòó lórí omi púpọ̀ hàn ọ́,+ 2 ẹni tí àwọn ọba ayé bá ṣe ìṣekúṣe,*+ tí a sì mú kí àwọn tó ń gbé ayé mu wáìnì ìṣekúṣe* rẹ̀ ní àmupara.”+