Sáàmù 137:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+ Jeremáyà 50:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ kígbe ogun mọ́ ọn láti ibi gbogbo. Ó ti juwọ́ sílẹ̀.* Àwọn òpó rẹ̀ ti ṣubú, àwọn ògiri rẹ̀ sì ti ya lulẹ̀,+Nítorí ẹ̀san Jèhófà ni.+ Ẹ gbẹ̀san lára rẹ̀. Bí ó ti ṣe síni ni kí ẹ ṣe sí i gẹ́lẹ́.+
8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+
15 Ẹ kígbe ogun mọ́ ọn láti ibi gbogbo. Ó ti juwọ́ sílẹ̀.* Àwọn òpó rẹ̀ ti ṣubú, àwọn ògiri rẹ̀ sì ti ya lulẹ̀,+Nítorí ẹ̀san Jèhófà ni.+ Ẹ gbẹ̀san lára rẹ̀. Bí ó ti ṣe síni ni kí ẹ ṣe sí i gẹ́lẹ́.+