2 Pétérù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ ọjọ́ Jèhófà*+ máa dé bí olè,+ nígbà yẹn àwọn ọ̀run máa kọjá lọ+ pẹ̀lú ariwo tó rinlẹ̀,* àmọ́ àwọn ohun ìpìlẹ̀ tó gbóná janjan máa yọ́, a sì máa tú ayé àti àwọn iṣẹ́ tó wà nínú rẹ̀ síta.+ Ìfihàn 20:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Mo rí ìtẹ́ funfun kan tó tóbi àti Ẹni tó jókòó sórí rẹ̀.+ Ayé àti ọ̀run sá kúrò níwájú rẹ̀,+ kò sì sí àyè kankan fún wọn.
10 Àmọ́ ọjọ́ Jèhófà*+ máa dé bí olè,+ nígbà yẹn àwọn ọ̀run máa kọjá lọ+ pẹ̀lú ariwo tó rinlẹ̀,* àmọ́ àwọn ohun ìpìlẹ̀ tó gbóná janjan máa yọ́, a sì máa tú ayé àti àwọn iṣẹ́ tó wà nínú rẹ̀ síta.+
11 Mo rí ìtẹ́ funfun kan tó tóbi àti Ẹni tó jókòó sórí rẹ̀.+ Ayé àti ọ̀run sá kúrò níwájú rẹ̀,+ kò sì sí àyè kankan fún wọn.