ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hábákúkù 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Hábákúkù

      • Wòlíì náà ké pe Jèhófà pé kó ran òun lọ́wọ́ (1-4)

        • “Jèhófà, báwo ló ṣe máa pẹ́ tó?” (2)

        • ‘Kí nìdí tí o fi fàyè gba ìnilára?’ (3)

      • Ọlọ́run lo àwọn ará Kálídíà láti ṣèdájọ́ (5-11)

      • Wòlíì náà bẹ Jèhófà (12-17)

        • ‘Ọlọ́run mi, ìwọ kì í kú’ (12)

        • ‘O ti mọ́ jù láti máa wo ohun búburú’ (13)

Hábákúkù 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣeé ṣe kó túmọ̀ sí “Gbáni Mọ́ra Tọkàntọkàn.”

Hábákúkù 1:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbani là.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 13:1
  • +Sm 22:1; 74:10; Ifi 6:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 14-15

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2000, ojú ìwé 19

    2/1/2000, ojú ìwé 8-9

    1/15/2000, ojú ìwé 10

    12/15/1999, ojú ìwé 21

Hábákúkù 1:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 14-15

    Ayọ, ojú ìwé 132-133

Hábákúkù 1:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 12:6; Sm 12:8; Onw 8:11; Ais 1:21; Iṣe 7:52, 53

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 8-9

    Ayọ, ojú ìwé 132-133

Hábákúkù 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 28:21; 29:14; Ida 4:11, 12; Iṣe 13:40, 41

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 15

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    11/2017, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 10

    2/1/2000, ojú ìwé 10-11, 13

    6/1/1991, ojú ìwé 22

Hábákúkù 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 22:7; 46:2
  • +Di 28:49-51; Jer 5:15-17; 6:22, 23; Isk 23:22, 23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 15

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    11/2017, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 10

    2/1/2000, ojú ìwé 11

Hábákúkù 1:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “iyì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 39:5-7; Da 5:18, 19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 11

Hábákúkù 1:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 5:6
  • +Jer 4:13; Ida 4:19; Isk 17:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 11

Hábákúkù 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:9
  • +Ais 27:8; Isk 17:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 11

Hábákúkù 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 24:12
  • +Jer 32:24; 52:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 11

Hábákúkù 1:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “agbára wọn ni ọlọ́run wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 47:5, 6; Jer 51:24; Sek 1:15
  • +Da 5:1, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 11

Hábákúkù 1:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “àwa kò ní kú.”

  • *

    Tàbí “láti báni wí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 90:2; 93:2; Ifi 1:8
  • +1Ti 1:17; Ifi 15:3
  • +Di 32:4
  • +Jer 30:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 15

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 11-12

    3/1/1991, ojú ìwé 29

Hábákúkù 1:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 5:4, 5
  • +Jer 12:1
  • +Sm 35:21, 22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 15

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 12

Hábákúkù 1:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2000, ojú ìwé 12

Hábákúkù 1:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, àwọn ará Kálídíà tó jẹ́ ọ̀tá.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:11

Hábákúkù 1:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “èéfín ẹbọ.”

  • *

    Ní Héb., “òróró dun oúnjẹ rẹ̀.”

Hábákúkù 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “máa fa idà rẹ̀ yọ?”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:17; Na 3:7

Àwọn míì

Háb. 1:2Sm 13:1
Háb. 1:2Sm 22:1; 74:10; Ifi 6:10
Háb. 1:4Job 12:6; Sm 12:8; Onw 8:11; Ais 1:21; Iṣe 7:52, 53
Háb. 1:5Ais 28:21; 29:14; Ida 4:11, 12; Iṣe 13:40, 41
Háb. 1:6Jer 22:7; 46:2
Háb. 1:6Di 28:49-51; Jer 5:15-17; 6:22, 23; Isk 23:22, 23
Háb. 1:7Jer 39:5-7; Da 5:18, 19
Háb. 1:8Jer 5:6
Háb. 1:8Jer 4:13; Ida 4:19; Isk 17:3
Háb. 1:9Ais 27:8; Isk 17:10
Háb. 1:9Jer 25:9
Háb. 1:102Ọb 24:12
Háb. 1:10Jer 32:24; 52:7
Háb. 1:11Ais 47:5, 6; Jer 51:24; Sek 1:15
Háb. 1:11Da 5:1, 4
Háb. 1:12Sm 90:2; 93:2; Ifi 1:8
Háb. 1:121Ti 1:17; Ifi 15:3
Háb. 1:12Di 32:4
Háb. 1:12Jer 30:11
Háb. 1:13Sm 5:4, 5
Háb. 1:13Jer 12:1
Háb. 1:13Sm 35:21, 22
Háb. 1:15Jer 50:11
Háb. 1:172Kr 36:17; Na 3:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Hábákúkù 1:1-17

Hábákúkù

1 Ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run sọ fún wòlíì Hábákúkù* nínú ìran pé kó kéde nìyí:

 2 Jèhófà, báwo ló ṣe máa pẹ́ tó tí màá fi ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́ àmọ́ tí o kò gbọ́?+

Báwo ló ṣe máa pẹ́ tó tí màá fi ké pè ọ́ pé kí o gbà mí lọ́wọ́ ìwà ipá àmọ́ tí o kò dá sí i?*+

 3 Kí nìdí tí o fi ń jẹ́ kí ohun búburú ṣẹlẹ̀ níṣojú mi?

Kí sì nìdí tí o fi fàyè gba ìnilára?

Kí nìdí tí ìparun àti ìwà ipá fi ń ṣẹlẹ̀ níṣojú mi?

Kí sì nìdí tí ìjà àti aáwọ̀ fi wà káàkiri?

 4 Òfin kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ mọ́,

Kò sì sí ìdájọ́ òdodo rárá.

Torí àwọn ẹni ibi yí olódodo ká;

Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń yí ìdájọ́ po.+

 5 “Ẹ wo àwọn orílẹ̀-èdè kí ẹ sì kíyè sí i!

Kí ẹnu yà yín bí ẹ ṣe ń wò wọ́n, kí ó sì jọ yín lójú;

Torí ohun kan máa ṣẹlẹ̀ lásìkò yín,

Tí ẹ ò ní gbà gbọ́ tí wọ́n bá tiẹ̀ sọ ọ́ fún yín.+

 6 Mò ń gbé àwọn ará Kálídíà dìde,+

Orílẹ̀-èdè tí kò lójú àánú, tí kì í fi nǹkan falẹ̀.

Wọ́n yára bolẹ̀ káàkiri ayé

Láti gba àwọn ilé tí kì í ṣe tiwọn.+

 7 Wọ́n ń dẹ́rù bani, wọ́n sì ń kóni láyà jẹ.

Wọ́n ń gbé ìdájọ́ àti àṣẹ* tiwọn kalẹ̀.+

 8 Àwọn ẹṣin wọn yára ju àmọ̀tẹ́kùn lọ,

Wọ́n sì burú ju ìkookò ní alẹ́.+

Àwọn ẹṣin ogun wọn ń bẹ́ gìjàgìjà;

Ọ̀nà jíjìn làwọn ẹṣin wọn ti wá.

Wọ́n já ṣòòrò wálẹ̀ bí ẹyẹ idì tó fẹ́ yára gbé oúnjẹ.+

 9 Torí wọ́n fẹ́ hùwà ipá ni wọ́n ṣe wá.+

Gbogbo wọn kọjú síbì kan náà bí afẹ́fẹ́ tó ń fẹ́ bọ̀ láti ìlà oòrùn,+

Wọ́n sì ń kó àwọn èèyàn lẹ́rú bí ẹni ń kó iyanrìn.

10 Wọ́n ń fi àwọn ọba ṣe yẹ̀yẹ́,

Wọ́n sì ń fi àwọn ìjòyè ṣe ẹlẹ́yà.+

Wọ́n ń fi gbogbo ibi olódi rẹ́rìn-ín;+

Wọ́n fi iyẹ̀pẹ̀ mọ òkìtì, wọ́n sì gbà á.

11 Wọ́n rọ́ lọ síwájú bí afẹ́fẹ́, wọ́n sì fẹ́ kọjá,

Àmọ́ wọ́n máa jẹ̀bi,+

Torí wọ́n gbà pé ọlọ́run wọn ló ń fún wọn lágbára.”*+

12 Jèhófà, ṣebí láti ayérayé ni ìwọ ti wà?+

Ọlọ́run mi, Ẹni Mímọ́ mi, ìwọ kì í kú.*+

Jèhófà, ìwọ lo yàn wọ́n láti ṣèdájọ́;

Àpáta mi,+ o lò wọ́n láti fìyà jẹni.*+

13 Ojú rẹ ti mọ́ jù láti wo ohun búburú,

Ìwọ kò sì ní gba ìwà burúkú láyè.+

Kí ló wá dé tí o fi fàyè gba àwọn ọ̀dàlẹ̀,+

Tí o sì dákẹ́ títí ẹni burúkú fi gbé ẹni tó jẹ́ olódodo jù ú lọ mì?+

14 Kí nìdí tí o fi jẹ́ kí àwọn èèyàn dà bí ẹja inú òkun,

Bí àwọn ohun tó ń rákò, tí wọn ò ní olórí?

15 Ó* fi ìwọ̀ kó gbogbo wọn sókè.

Ó fi àwọ̀n rẹ̀ kó wọn,

Ó sì fi àwọ̀n ìpẹja rẹ̀ kó wọn jọ.

Ìdí nìyẹn tí inú rẹ̀ fi ń dùn ṣìnkìn.+

16 Ìdí nìyẹn tó fi ń rúbọ sí àwọ̀n rẹ̀,

Tó sì ń rú ẹbọ* sí àwọ̀n ìpẹja rẹ̀;

Torí wọ́n ń mú kí nǹkan ṣẹnuure fún un,*

Oúnjẹ tó dára jù ló sì ń jẹ.

17 Ṣé gbogbo ìgbà ni yóò máa kó nǹkan jáde nínú àwọ̀n rẹ̀ ni?*

Ṣé bí á ṣe máa pa àwọn orílẹ̀-èdè lọ láì ṣàánú wọn nìyí?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́