ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 20
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kíróníkà

      • Wọ́n gba Rábà (1-3)

      • Wọ́n pa àwọn òmìrán Filísínì (4-8)

1 Kíróníkà 20:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, nígbà ìrúwé.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 11:6
  • +Di 3:11
  • +2Sa 11:1
  • +2Sa 12:26

1 Kíróníkà 20:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tálẹ́ńtì kan jẹ́ kìlógíráàmù 34.2. Wo Àfikún B14.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 8:11, 12; 12:30, 31

1 Kíróníkà 20:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 9:20, 21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2005, ojú ìwé 27

1 Kíróníkà 20:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 21:18; 1Kr 11:26, 29
  • +Di 3:13

1 Kíróníkà 20:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “olófì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:4, 7; 21:9
  • +2Sa 21:19; 1Kr 11:23, 24

1 Kíróníkà 20:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 11:22; 1Sa 7:14
  • +Nọ 13:33; Di 2:10; 3:11
  • +2Sa 21:16, 20-22

1 Kíróníkà 20:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 17:10; 2Ọb 19:22
  • +1Kr 2:13

1 Kíróníkà 20:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 2:11
  • +1Sa 17:4

Àwọn míì

1 Kíró. 20:11Kr 11:6
1 Kíró. 20:1Di 3:11
1 Kíró. 20:12Sa 11:1
1 Kíró. 20:12Sa 12:26
1 Kíró. 20:22Sa 8:11, 12; 12:30, 31
1 Kíró. 20:31Ọb 9:20, 21
1 Kíró. 20:42Sa 21:18; 1Kr 11:26, 29
1 Kíró. 20:4Di 3:13
1 Kíró. 20:51Sa 17:4, 7; 21:9
1 Kíró. 20:52Sa 21:19; 1Kr 11:23, 24
1 Kíró. 20:6Joṣ 11:22; 1Sa 7:14
1 Kíró. 20:6Nọ 13:33; Di 2:10; 3:11
1 Kíró. 20:62Sa 21:16, 20-22
1 Kíró. 20:71Sa 17:10; 2Ọb 19:22
1 Kíró. 20:71Kr 2:13
1 Kíró. 20:8Di 2:11
1 Kíró. 20:81Sa 17:4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kíróníkà 20:1-8

Kíróníkà Kìíní

20 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún,* lákòókò tí àwọn ọba máa ń jáde ogun, Jóábù+ kó àwùjọ ọmọ ogun kan jáde, ó sì run ilẹ̀ àwọn ọmọ Ámónì; ó wá dó ti Rábà,+ àmọ́ Dáfídì dúró sí Jerúsálẹ́mù.+ Jóábù gbéjà ko Rábà, ó sì wó o palẹ̀.+ 2 Nígbà náà, Dáfídì mú adé Málíkámù kúrò ní orí rẹ̀, ó sì rí i pé ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ tálẹ́ńtì* wúrà kan àti pé àwọn òkúta iyebíye wà lára rẹ̀; a sì fi dé Dáfídì lórí. Ó tún kó ẹrù tó pọ̀ gan-an látinú ìlú náà.+ 3 Ó kó àwọn èèyàn inú rẹ̀, ó fi wọ́n sídìí iṣẹ́+ pé kí wọ́n máa fi ayùn rẹ́ òkúta, kí wọ́n sì máa fi àwọn ohun èlò onírin mímú àti àáké ṣiṣẹ́. Ohun tí Dáfídì ṣe sí gbogbo àwọn ìlú àwọn ọmọ Ámónì nìyẹn. Níkẹyìn, Dáfídì àti gbogbo àwọn ọmọ ogun náà pa dà sí Jerúsálẹ́mù.

4 Lẹ́yìn èyí, wọ́n bá àwọn Filísínì jà ní Gésérì. Ìgbà yẹn ni Síbékáì + ọmọ Húṣà pa Sípáì tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àtọmọdọ́mọ Réfáímù,+ wọ́n sì ṣẹ́gun àwọn Filísínì.

5 Wọ́n tún bá àwọn Filísínì jà, Élíhánánì ọmọ Jáírì pa Láámì arákùnrin Gòláyátì+ ará Gátì, ẹni tí igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ.*+

6 Ogun tún wáyé ní Gátì,+ níbi tí ọkùnrin kan wà tí ó tóbi fàkìàfakia,+ ó ní ìka mẹ́fà-mẹ́fà ní ọwọ́ àti ní ẹsẹ̀, gbogbo wọn jẹ́ mẹ́rìnlélógún (24); òun náà sì wà lára àwọn àtọmọdọ́mọ Réfáímù.+ 7 Ó ń pẹ̀gàn+ Ísírẹ́lì. Torí náà, Jónátánì ọmọ Ṣíméà,+ ẹ̀gbọ́n Dáfídì, pa á.

8 Àwọn yìí jẹ́ àtọmọdọ́mọ Réfáímù+ ní Gátì,+ Dáfídì àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ló sì pa wọ́n.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́