ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìsíkíẹ́lì

      • Àwọn ọkùnrin mẹ́fà tó ń pààyàn àti ọkùnrin kan tó ní ìwo yíǹkì (1-11)

        • Ìdájọ́ máa bẹ̀rẹ̀ ní ibi mímọ́ (6)

Ìsíkíẹ́lì 9:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 172-173

Ìsíkíẹ́lì 9:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aṣọ àtàtà.”

  • *

    Tàbí “ibi tí akọ̀wé ń rọ yíǹkì sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 20:2; Isk 8:3
  • +2Kr 4:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 173, 175, 238

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    6/2017, ojú ìwé 6

Ìsíkíẹ́lì 9:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 3:23; 8:3, 4; 11:22
  • +Isk 10:4

Ìsíkíẹ́lì 9:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 119:53; 2Pe 2:7, 8
  • +Isk 5:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 173-175, 176-180

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    6/2017, ojú ìwé 6

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    6/2016, ojú ìwé 16-17

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 5-6

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 124

    Ìmọ̀, ojú ìwé 180

Ìsíkíẹ́lì 9:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 32:26, 27; Isk 7:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 174-175, 180

Ìsíkíẹ́lì 9:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:17
  • +Ẹk 12:23; Joṣ 2:17-19; Ifi 9:4
  • +2Ọb 25:18, 21; Jer 25:29
  • +Isk 8:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 174-175, 179-180

Ìsíkíẹ́lì 9:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ida 2:21

Ìsíkíẹ́lì 9:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 18:23; Isk 11:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 176

Ìsíkíẹ́lì 9:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:14; Ais 1:4
  • +2Ọb 21:16; Jer 2:34; Mt 23:30
  • +Isk 22:29
  • +Ais 29:15; Isk 8:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 176

Ìsíkíẹ́lì 9:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 5:11; 7:4

Àwọn míì

Ìsík. 9:2Jer 20:2; Isk 8:3
Ìsík. 9:22Kr 4:1
Ìsík. 9:3Isk 3:23; 8:3, 4; 11:22
Ìsík. 9:3Isk 10:4
Ìsík. 9:4Sm 119:53; 2Pe 2:7, 8
Ìsík. 9:4Isk 5:11
Ìsík. 9:5Ẹk 32:26, 27; Isk 7:4
Ìsík. 9:62Kr 36:17
Ìsík. 9:6Ẹk 12:23; Joṣ 2:17-19; Ifi 9:4
Ìsík. 9:62Ọb 25:18, 21; Jer 25:29
Ìsík. 9:6Isk 8:11
Ìsík. 9:7Ida 2:21
Ìsík. 9:8Jẹ 18:23; Isk 11:13
Ìsík. 9:92Kr 36:14; Ais 1:4
Ìsík. 9:92Ọb 21:16; Jer 2:34; Mt 23:30
Ìsík. 9:9Isk 22:29
Ìsík. 9:9Ais 29:15; Isk 8:12
Ìsík. 9:10Isk 5:11; 7:4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ìsíkíẹ́lì 9:1-11

Ìsíkíẹ́lì

9 Lẹ́yìn náà, ó fi ohùn tó dún ketekete bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: “Pe àwọn tí yóò fìyà jẹ ìlú náà wá, kí kálukú wọn mú ohun ìjà tó máa fi pa á run dání!”

2 Mo rí ọkùnrin mẹ́fà tí wọ́n ń bọ̀ láti ẹnubodè apá òkè,+ tó dojú kọ àríwá, kálukú mú ohun ìjà tí wọ́n fi ń fọ́ nǹkan dání; ọkùnrin kan wà lára wọn tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀,* ìwo yíǹkì akọ̀wé* sì wà ní ìbàdí rẹ̀. Wọ́n wọlé, wọ́n sì dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ bàbà.+

3 Ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ wá gbéra lórí àwọn kérúbù níbi tó wà tẹ́lẹ̀, lọ sí ẹnu ọ̀nà ilé náà,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í pe ọkùnrin tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ náà, tí ìwo yíǹkì akọ̀wé wà ní ìbàdí rẹ̀. 4 Jèhófà sọ fún un pé: “Lọ káàkiri ìlú náà, káàkiri Jerúsálẹ́mù, kí o sì sàmì sí iwájú orí àwọn èèyàn tó ń kẹ́dùn, tí wọ́n sì ń kérora+ torí gbogbo ohun ìríra tí wọ́n ń ṣe ní ìlú náà.”+

5 Mo sì gbọ́ tó sọ fún àwọn yòókù pé: “Ẹ tẹ̀ lé e káàkiri ìlú náà, kí ẹ sì pa wọ́n. Ẹ má ṣàánú wọn, ẹ má sì yọ́nú sí wọn rárá.+ 6 Ẹ pa àwọn àgbàlagbà ọkùnrin pátápátá àti àwọn géńdé ọkùnrin, wúńdíá, ọmọdé àti àwọn obìnrin.+ Àmọ́ ẹ má ṣe sún mọ́ ẹnikẹ́ni tí àmì náà wà lórí rẹ̀.+ Ibi mímọ́ mi ni kí ẹ ti bẹ̀rẹ̀.”+ Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ látorí àwọn àgbààgbà tí wọ́n wà níwájú ilé náà.+ 7 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ sọ ilé náà di ẹlẹ́gbin, kí ẹ sì fi òkú èèyàn kún inú àwọn àgbàlá.+ Ẹ lọ!” Ni wọ́n bá lọ, wọ́n sì pa àwọn èèyàn ní ìlú náà.

8 Bí wọ́n ṣe ń pa wọ́n, ó wá ku èmi nìkan, mo bá dojú bolẹ̀, mo sì ké jáde pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Ṣé inú tó ń bí ọ sí Jerúsálẹ́mù máa mú kí o pa gbogbo àwọn tó ṣẹ́ kù ní Ísírẹ́lì run ni?”+

9 Torí náà, ó sọ fún mi pé: “Ẹ̀ṣẹ̀ ilé Ísírẹ́lì àti Júdà pọ̀ gidigidi.+ Ìtàjẹ̀sílẹ̀ kún ilẹ̀ náà,+ ìwà ìbàjẹ́ sì kún ìlú náà.+ Wọ́n ń sọ pé, ‘Jèhófà ti fi ilẹ̀ wa sílẹ̀, Jèhófà ò sì rí wa.’+ 10 Àmọ́ ní tèmi, mi ò ní ṣàánú wọn, mi ò sì ní yọ́nú sí wọn.+ Màá fi ìwà wọn san wọ́n lẹ́san.”

11 Mo wá rí ọkùnrin tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀, tí ìwo yíǹkì wà ní ìbàdí rẹ̀, ó pa dà wá jíṣẹ́ pé: “Mo ti ṣe ohun tí o pa láṣẹ fún mi.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́