Sáàmù
Orin Ìgòkè. Ti Dáfídì.
2 Àmọ́, mo ti tu ọkàn* mi lára, mo sì ti mú kó pa rọ́rọ́ +
Bí ọmọ tí a ti gba ọmú lẹ́nu rẹ̀, tó wà lọ́dọ̀ ìyá rẹ̀;
Mo* ní ìtẹ́lọ́rùn bí ọmọ tí a ti gba ọmú lẹ́nu rẹ̀.
3 Kí Ísírẹ́lì dúró de Jèhófà+
Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.