ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 24
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́kísódù

      • Àwọn èèyàn gbà láti pa májẹ̀mú mọ́ (1-11)

      • Mósè lọ sórí Òkè Sínáì (12-18)

Ẹ́kísódù 24:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 10:1

Ẹ́kísódù 24:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 20:21; Nọ 12:8

Ẹ́kísódù 24:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 21:1; Di 4:1
  • +Di 5:27; Joṣ 24:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 110

Ẹ́kísódù 24:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:27; Di 31:9

Ẹ́kísódù 24:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 3:1; 7:11

Ẹ́kísódù 24:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 109-110

Ẹ́kísódù 24:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 31:11; Iṣe 13:15
  • +Ẹk 19:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 11/2020, ojú ìwé 6

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1995, ojú ìwé 9, 11

    3/1/1995, ojú ìwé 11

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 109-110

Ẹ́kísódù 24:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 12:24
  • +Heb 9:18-20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 109-110

Ẹ́kísódù 24:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:18
  • +Isk 1:26; Ifi 4:3

Ẹ́kísódù 24:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 24:1

Ẹ́kísódù 24:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 5:22

Ẹ́kísódù 24:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 11:28
  • +Ẹk 24:2

Ẹ́kísódù 24:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 32:1
  • +Ẹk 17:10
  • +Ẹk 18:25, 26

Ẹ́kísódù 24:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọsánmà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:9

Ẹ́kísódù 24:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 16:10; Le 9:23; Nọ 16:42
  • +Ẹk 19:11

Ẹ́kísódù 24:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:20
  • +Ẹk 34:28; Di 9:9

Àwọn míì

Ẹ́kís. 24:1Le 10:1
Ẹ́kís. 24:2Ẹk 20:21; Nọ 12:8
Ẹ́kís. 24:3Ẹk 21:1; Di 4:1
Ẹ́kís. 24:3Di 5:27; Joṣ 24:22
Ẹ́kís. 24:4Ẹk 34:27; Di 31:9
Ẹ́kís. 24:5Le 3:1; 7:11
Ẹ́kís. 24:7Di 31:11; Iṣe 13:15
Ẹ́kís. 24:7Ẹk 19:8
Ẹ́kís. 24:8Heb 12:24
Ẹ́kís. 24:8Heb 9:18-20
Ẹ́kís. 24:10Jo 1:18
Ẹ́kís. 24:10Isk 1:26; Ifi 4:3
Ẹ́kís. 24:11Ẹk 24:1
Ẹ́kís. 24:12Di 5:22
Ẹ́kís. 24:13Nọ 11:28
Ẹ́kís. 24:13Ẹk 24:2
Ẹ́kís. 24:14Ẹk 32:1
Ẹ́kís. 24:14Ẹk 17:10
Ẹ́kís. 24:14Ẹk 18:25, 26
Ẹ́kís. 24:15Ẹk 19:9
Ẹ́kís. 24:16Ẹk 16:10; Le 9:23; Nọ 16:42
Ẹ́kís. 24:16Ẹk 19:11
Ẹ́kís. 24:18Ẹk 19:20
Ẹ́kís. 24:18Ẹk 34:28; Di 9:9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ẹ́kísódù 24:1-18

Ẹ́kísódù

24 Ó wá sọ fún Mósè pé: “Kí ìwọ àti Áárónì gòkè lọ sọ́dọ̀ Jèhófà, pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù+ àti àádọ́rin (70) nínú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì, kí ẹ sì tẹrí ba láti òkèèrè. 2 Mósè nìkan ni kó sún mọ́ ọ̀dọ̀ Jèhófà; kí àwọn tó kù má ṣe sún mọ́ ibẹ̀, kí àwọn èèyàn náà má sì bá a gòkè.”+

3 Lẹ́yìn náà, Mósè wá, ó sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ Jèhófà àti gbogbo ìdájọ́ náà+ fún àwọn èèyàn, gbogbo àwọn èèyàn náà sì fohùn ṣọ̀kan, wọ́n fèsì pé: “Gbogbo ohun tí Jèhófà sọ la múra tán láti ṣe.”+ 4 Mósè wá kọ gbogbo ọ̀rọ̀ Jèhófà sílẹ̀.+ Ó dìde ní àárọ̀ kùtù, ó sì mọ pẹpẹ kan sísàlẹ̀ òkè náà àti òpó méjìlá (12) tó dúró fún ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì. 5 Lẹ́yìn náà, ó rán àwọn ọ̀dọ́kùnrin tó jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n rú ẹbọ sísun, wọ́n sì fi àwọn akọ màlúù rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ sí Jèhófà. 6 Mósè wá mú ìdajì lára ẹ̀jẹ̀ náà, ó dà á sínú àwọn abọ́, ó sì wọ́n ìdajì sórí pẹpẹ. 7 Lẹ́yìn náà, ó mú ìwé májẹ̀mú, ó kà á sókè fún àwọn èèyàn náà.+ Wọ́n sì sọ pé: “Gbogbo ohun tí Jèhófà sọ la múra tán láti ṣe, a ó sì máa ṣègbọràn.”+ 8 Mósè wọ́n ẹ̀jẹ̀ náà sára àwọn èèyàn náà,+ ó sì sọ pé: “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú tí Jèhófà bá yín dá pẹ̀lú gbogbo ọ̀rọ̀ yìí.”+

9 Mósè àti Áárónì, Nádábù àti Ábíhù àti àádọ́rin (70) nínú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì wá gòkè lọ, 10 wọ́n sì rí Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+ Ohun tó dà bíi pèpéle òkúta sàfáyà wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, ó sì mọ́ nigínnigín bí ọ̀run.+ 11 Kò pa àwọn èèyàn pàtàkì yìí nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lára,+ wọ́n sì rí ìran Ọlọ́run tòótọ́, wọ́n jẹ, wọ́n sì mu.

12 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wá bá mi lórí òkè, kí o sì dúró síbẹ̀. Màá fún ọ ní àwọn wàláà òkúta tí èmi yóò kọ òfin àti àṣẹ sí láti fún àwọn èèyàn náà ní ìtọ́ni.”+ 13 Mósè gbéra pẹ̀lú Jóṣúà ìránṣẹ́ rẹ̀,+ Mósè sì lọ sórí òkè Ọlọ́run tòótọ́.+ 14 Àmọ́ ó ti sọ fún àwọn àgbààgbà náà pé: “Ẹ dúró dè wá níbí títí a ó fi pa dà wá bá yín.+ Áárónì àti Húrì+ wà pẹ̀lú yín. Tí ẹnikẹ́ni bá ní ẹjọ́, kó lọ bá wọn.”+ 15 Mósè wá lọ sórí òkè náà nígbà tí ìkùukùu* ṣì bo òkè náà.+

16 Ògo Jèhófà+ ò kúrò lórí Òkè Sínáì,+ ìkùukùu náà sì bò ó fún ọjọ́ mẹ́fà. Ní ọjọ́ keje, ó pe Mósè látinú ìkùukùu náà. 17 Lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó ń wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀, ògo Jèhófà rí bí iná tó ń jẹ nǹkan run lórí òkè náà. 18 Mósè wá wọ inú ìkùukùu náà, ó sì lọ sórí òkè náà.+ Mósè sì dúró lórí òkè náà fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́