ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 18
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kíróníkà

      • Àwọn tí Dáfídì ṣẹ́gun (1-13)

      • Ìjọba Dáfídì (14-17)

1 Kíróníkà 18:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìlú tó yí i ká.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 5:8; 2Sa 1:20
  • +2Sa 8:1

1 Kíróníkà 18:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “owó òde.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 24:17; Sm 60:8
  • +2Sa 8:2; 2Ọb 3:4

1 Kíróníkà 18:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 11:23
  • +1Sa 14:47; 2Sa 10:6; Sm 60:àkọlé
  • +2Kr 8:3
  • +Jẹ 15:18; Ẹk 23:31; 2Sa 8:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2005, ojú ìwé 11

1 Kíróníkà 18:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “pátì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 20:7
  • +Di 17:16; Sm 33:17

1 Kíróníkà 18:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 8:5-8

1 Kíróníkà 18:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “owó òde.”

  • *

    Tàbí “gba Dáfídì là.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 17:8

1 Kíróníkà 18:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “apata ribiti.”

1 Kíróníkà 18:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 7:23
  • +1Ọb 7:15, 45

1 Kíróníkà 18:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 8:3
  • +2Sa 8:9-11

1 Kíróníkà 18:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 6:19; 2Kr 5:1
  • +1Kr 20:1
  • +2Sa 5:25
  • +1Sa 27:8, 9; 30:18, 20

1 Kíróníkà 18:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 26:6; 2Sa 3:30; 10:10; 20:6; 21:17
  • +1Kr 2:15, 16
  • +2Sa 8:13, 14

1 Kíróníkà 18:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gba Dáfídì là.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 25:23; 27:40
  • +Sm 18:48; 144:10

1 Kíróníkà 18:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 2:11
  • +2Sa 8:15-18; 23:3, 4; Sm 78:70-72

1 Kíróníkà 18:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 11:6
  • +1Ọb 4:3

1 Kíróníkà 18:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Sa 30:14; Sef 2:5
  • +1Ọb 1:38

Àwọn míì

1 Kíró. 18:11Sa 5:8; 2Sa 1:20
1 Kíró. 18:12Sa 8:1
1 Kíró. 18:2Nọ 24:17; Sm 60:8
1 Kíró. 18:22Sa 8:2; 2Ọb 3:4
1 Kíró. 18:31Ọb 11:23
1 Kíró. 18:31Sa 14:47; 2Sa 10:6; Sm 60:àkọlé
1 Kíró. 18:32Kr 8:3
1 Kíró. 18:3Jẹ 15:18; Ẹk 23:31; 2Sa 8:3, 4
1 Kíró. 18:4Sm 20:7
1 Kíró. 18:4Di 17:16; Sm 33:17
1 Kíró. 18:52Sa 8:5-8
1 Kíró. 18:61Kr 17:8
1 Kíró. 18:81Ọb 7:23
1 Kíró. 18:81Ọb 7:15, 45
1 Kíró. 18:92Sa 8:3
1 Kíró. 18:92Sa 8:9-11
1 Kíró. 18:11Joṣ 6:19; 2Kr 5:1
1 Kíró. 18:111Kr 20:1
1 Kíró. 18:112Sa 5:25
1 Kíró. 18:111Sa 27:8, 9; 30:18, 20
1 Kíró. 18:121Sa 26:6; 2Sa 3:30; 10:10; 20:6; 21:17
1 Kíró. 18:121Kr 2:15, 16
1 Kíró. 18:122Sa 8:13, 14
1 Kíró. 18:13Jẹ 25:23; 27:40
1 Kíró. 18:13Sm 18:48; 144:10
1 Kíró. 18:141Ọb 2:11
1 Kíró. 18:142Sa 8:15-18; 23:3, 4; Sm 78:70-72
1 Kíró. 18:151Kr 11:6
1 Kíró. 18:151Ọb 4:3
1 Kíró. 18:171Sa 30:14; Sef 2:5
1 Kíró. 18:171Ọb 1:38
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kíróníkà 18:1-17

Kíróníkà Kìíní

18 Nígbà tó yá, Dáfídì ṣẹ́gun àwọn Filísínì, ó borí wọn, Dáfídì sì gba Gátì+ àti àwọn àrọko* rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn Filísínì.+ 2 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ṣẹ́gun Móábù,+ àwọn ọmọ Móábù wá di ìránṣẹ́ rẹ̀, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀*+ wá.

3 Dáfídì ṣẹ́gun Hadadésà+ ọba Sóbà+ nítòsí Hámátì,+ bí ó ṣe ń lọ fìdí àkóso rẹ̀ múlẹ̀ ní odò Yúfírétì.+ 4 Dáfídì gba ẹgbẹ̀rún (1,000) kẹ̀kẹ́ ẹṣin, ẹgbẹ̀rún méje (7,000) agẹṣin àti ọ̀kẹ́ kan (20,000) ọmọ ogun tó ń fẹsẹ̀ rìn lọ́wọ́ rẹ̀.+ Dáfídì sì já iṣan ẹsẹ̀* gbogbo àwọn ẹṣin tó ń fa kẹ̀kẹ́ ogun, àmọ́ ó dá ọgọ́rùn-ún (100) lára àwọn ẹṣin náà sí.+ 5 Nígbà tí àwọn ará Síríà tó wà ní Damásíkù wá ran Hadadésà ọba Sóbà lọ́wọ́, Dáfídì pa ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) lára àwọn ará Síríà náà.+ 6 Lẹ́yìn náà, Dáfídì fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí Damásíkù ní Síríà, àwọn ará Síríà wá di ìránṣẹ́ Dáfídì, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀* wá. Jèhófà sì ń jẹ́ kí Dáfídì ṣẹ́gun* ní ibikíbi tó bá lọ.+ 7 Láfikún sí i, Dáfídì gba àwọn apata* wúrà tó wà lọ́wọ́ àwọn ìránṣẹ́ Hadadésà, ó sì kó wọn wá sí Jerúsálẹ́mù. 8 Dáfídì kó bàbà tó pọ̀ gan-an láti Tíbátì àti Kúnì, àwọn ìlú Hadadésà. Òun ni Sólómọ́nì fi ṣe Òkun bàbà+ àti àwọn òpó pẹ̀lú àwọn nǹkan èlò bàbà.+

9 Nígbà tí Tóù ọba Hámátì gbọ́ pé Dáfídì ti ṣẹ́gun gbogbo àwọn ọmọ ogun Hadadésà+ ọba Sóbà,+ 10 lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó rán Hádórámù ọmọkùnrin rẹ̀ sí Ọba Dáfídì pé kí ó lọ béèrè àlàáfíà rẹ̀, kí ó sì bá a yọ̀ torí pé ó ti bá Hadadésà jà, ó sì ṣẹ́gun rẹ̀ (nítorí Hadadésà ti máa ń bá Tóù jà tẹ́lẹ̀), ó sì kó oríṣiríṣi ohun èlò wúrà, ohun èlò fàdákà àti ohun èlò bàbà wá. 11 Ọba Dáfídì yà wọ́n sí mímọ́ fún Jèhófà+ pẹ̀lú fàdákà àti wúrà tó kó lọ́dọ̀ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yìí: láti Édómù àti Móábù, látọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ámónì,+ àwọn Filísínì+ àti àwọn ọmọ Ámálékì.+

12 Ábíṣáì+ ọmọ Seruáyà + pa ẹgbẹ̀rún méjìdínlógún (18,000) lára àwọn ọmọ Édómù ní Àfonífojì Iyọ̀.+ 13 Ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí Édómù, gbogbo àwọn ọmọ Édómù sì di ìránṣẹ́ Dáfídì.+ Jèhófà sì ń jẹ́ kí Dáfídì ṣẹ́gun* ní ibikíbi tó bá lọ.+ 14 Dáfídì ń jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì,+ ó ń dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, ó sì ń ṣe òdodo sí gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀.+ 15 Jóábù ọmọ Seruáyà ni olórí àwọn ọmọ ogun,+ Jèhóṣáfátì+ ọmọ Áhílúdù sì ni akọ̀wé ìrántí, 16 Sádókù ọmọ Áhítúbù àti Áhímélékì ọmọ Ábíátárì ni àlùfáà, Ṣáfúṣà sì ni akọ̀wé. 17 Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà ni olórí àwọn Kérétì+ àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+ Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì ló sì wà ní ipò iwájú lẹ́yìn ọba.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́