ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Jòhánù 5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Jòhánù

      • Ẹni tó bá gba Jésù gbọ́ ti ṣẹ́gun ayé (1-12)

        • Ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run túmọ̀ sí (3)

      • Ohun tó dá wa lójú nípa agbára tí àdúrà ní (13-17)

      • Ẹ máa ṣọ́ra nínú ayé tó burú (18-21)

        • Gbogbo ayé wà lábẹ́ agbára ẹni burúkú náà (19)

1 Jòhánù 5:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:3; 1Pe 1:3, 23; 1Jo 3:9

1 Jòhánù 5:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:12, 13; Ro 8:14

1 Jòhánù 5:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:23
  • +Di 30:11; Mik 6:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 8

    Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 186-187

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 311

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 5-12

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2009, ojú ìwé 25-26

    8/15/2009, ojú ìwé 19

    8/15/2005, ojú ìwé 27

    6/15/2002, ojú ìwé 22

    1/15/1997, ojú ìwé 19-22, 23-24

    12/15/1995, ojú ìwé 11

1 Jòhánù 5:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “gbogbo nǹkan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 16:33; 1Jo 5:18
  • +Ef 6:16; 2Ti 4:7; Ifi 12:10, 11

1 Jòhánù 5:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:4
  • +Jo 20:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 76

1 Jòhánù 5:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 3:13
  • +Iṣe 20:28; Ef 1:7; 1Pe 1:19
  • +Mt 3:16; Jo 1:32, 33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2008, ojú ìwé 28

1 Jòhánù 5:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 4 2016 ojú ìwé 6-7

    Jí!,

    No. 6 2016 ojú ìwé 11

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2014, ojú ìwé 15

    12/15/2008, ojú ìwé 28

    10/1/1997, ojú ìwé 13

1 Jòhánù 5:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 3:22; 4:18
  • +Lk 3:21
  • +Heb 9:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2008, ojú ìwé 28

1 Jòhánù 5:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:33

1 Jòhánù 5:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:3
  • +Jo 5:26

1 Jòhánù 5:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:36

1 Jòhánù 5:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 20:31
  • +1Jo 1:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 30

1 Jòhánù 5:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ohun tó jẹ́ ká máa bá a sọ̀rọ̀ fàlàlà ni pé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 4:16; 1Jo 3:21
  • +Owe 15:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2021 ojú ìwé 10

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 9

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2009, ojú ìwé 30

    8/15/2004, ojú ìwé 18

    Ìmọ̀, ojú ìwé 154-155

1 Jòhánù 5:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 11:13; Jo 14:13

1 Jòhánù 5:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 5:15; 1Jo 1:9
  • +Mt 12:31; Mk 3:29; Lk 12:10; Heb 6:4-6; 10:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2001, ojú ìwé 30-31

1 Jòhánù 5:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 3:4

1 Jòhánù 5:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Jésù Kristi, Ọmọ Ọlọ́run.

  • *

    Tàbí “dì í mú pinpin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:15

1 Jòhánù 5:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 13:19; Lk 4:6; Jo 12:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 26

    Jí!,

    No. 1 2021 ojú ìwé 10-11

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2014, ojú ìwé 16

    5/1/2013, ojú ìwé 4

    7/1/2010, ojú ìwé 22

    11/1/2002, ojú ìwé 15

1 Jòhánù 5:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “agbára ìmòye; làákàyè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 3:16
  • +Jo 17:20, 21
  • +Jo 17:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2012, ojú ìwé 6

    10/15/2004, ojú ìwé 30-31

1 Jòhánù 5:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 10:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 45

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/15/1993, ojú ìwé 24

Àwọn míì

1 Jòh. 5:1Jo 3:3; 1Pe 1:3, 23; 1Jo 3:9
1 Jòh. 5:2Jo 1:12, 13; Ro 8:14
1 Jòh. 5:3Jo 14:23
1 Jòh. 5:3Di 30:11; Mik 6:8
1 Jòh. 5:4Jo 16:33; 1Jo 5:18
1 Jòh. 5:4Ef 6:16; 2Ti 4:7; Ifi 12:10, 11
1 Jòh. 5:51Jo 4:4
1 Jòh. 5:5Jo 20:31
1 Jòh. 5:6Mt 3:13
1 Jòh. 5:6Iṣe 20:28; Ef 1:7; 1Pe 1:19
1 Jòh. 5:6Mt 3:16; Jo 1:32, 33
1 Jòh. 5:8Lk 3:22; 4:18
1 Jòh. 5:8Lk 3:21
1 Jòh. 5:8Heb 9:14
1 Jòh. 5:10Jo 3:33
1 Jòh. 5:11Jo 17:3
1 Jòh. 5:11Jo 5:26
1 Jòh. 5:12Jo 3:36
1 Jòh. 5:13Jo 20:31
1 Jòh. 5:131Jo 1:2
1 Jòh. 5:14Heb 4:16; 1Jo 3:21
1 Jòh. 5:14Owe 15:29
1 Jòh. 5:15Lk 11:13; Jo 14:13
1 Jòh. 5:16Jem 5:15; 1Jo 1:9
1 Jòh. 5:16Mt 12:31; Mk 3:29; Lk 12:10; Heb 6:4-6; 10:26
1 Jòh. 5:171Jo 3:4
1 Jòh. 5:18Jo 17:15
1 Jòh. 5:19Mt 13:19; Lk 4:6; Jo 12:31
1 Jòh. 5:201Ti 3:16
1 Jòh. 5:20Jo 17:20, 21
1 Jòh. 5:20Jo 17:3
1 Jòh. 5:211Kọ 10:14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Jòhánù 5:1-21

Ìwé Kìíní Jòhánù

5 Gbogbo ẹni tó bá gbà gbọ́ pé Jésù ni Kristi ni a ti bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ gbogbo ẹni tó bá sì nífẹ̀ẹ́ ẹni tó jẹ́ ká bí ẹnì kan, máa nífẹ̀ẹ́ ẹni tí onítọ̀hún bí. 2 Ohun tí a fi mọ̀ pé a nífẹ̀ẹ́ àwọn ọmọ Ọlọ́run+ nìyí, tí a bá nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run, tí a sì ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́. 3 Torí ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run túmọ̀ sí nìyí, pé ká pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́;+ síbẹ̀ àwọn àṣẹ rẹ̀ kò nira,+ 4 nítorí gbogbo ẹni* tí a ti bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ń ṣẹ́gun ayé.+ Ohun tó sì ṣẹ́gun ayé ni ìgbàgbọ́ wa.+

5 Ta ló lè ṣẹ́gun ayé?+ Ṣebí ẹni tó ní ìgbàgbọ́ pé Jésù ni Ọmọ Ọlọ́run ni?+ 6 Jésù Kristi ni ẹni tó wá nípasẹ̀ omi àti ẹ̀jẹ̀, kò wá nípasẹ̀ omi nìkan,+ àmọ́ nípasẹ̀ omi àti nípasẹ̀ ẹ̀jẹ̀.+ Ẹ̀mí sì ń jẹ́rìí,+ torí pé ẹ̀mí ni òtítọ́. 7 Nítorí àwọn mẹ́ta ló ń jẹ́rìí: 8 ẹ̀mí,+ omi+ àti ẹ̀jẹ̀;+ àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta sì wà níṣọ̀kan.

9 Tí a bá gba ẹ̀rí àwọn èèyàn, ẹ̀rí ti Ọlọ́run tóbi jù bẹ́ẹ̀ lọ. Torí ẹ̀rí tí Ọlọ́run fún wa nìyí, ẹ̀rí tó fún wa nípa Ọmọ rẹ̀. 10 Ẹni tó ní ìgbàgbọ́ nínú Ọmọ Ọlọ́run ní ẹ̀rí náà nínú ara rẹ̀. Ẹni tí kò ní ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run ti sọ ọ́ di òpùrọ́,+ torí kò ní ìgbàgbọ́ nínú ẹ̀rí tí Ọlọ́run fún wa nípa Ọmọ rẹ̀. 11 Ẹ̀rí náà sì nìyí, pé Ọlọ́run fún wa ní ìyè àìnípẹ̀kun,+ ìyè yìí sì wà nínú Ọmọ rẹ̀.+ 12 Ẹni tó ní Ọmọ ní ìyè yìí; ẹni tí kò bá ní Ọmọ Ọlọ́run kò ní ìyè yìí.+

13 Mo kọ àwọn nǹkan yìí sí ẹ̀yin tí ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú orúkọ Ọmọ Ọlọ́run,+ kí ẹ lè mọ̀ pé ẹ ní ìyè àìnípẹ̀kun.+ 14 Ohun tó dá wa lójú nípa rẹ̀ ni pé,*+ tí a bá béèrè ohunkóhun tó bá ìfẹ́ rẹ̀ mu, ó ń gbọ́ wa.+ 15 Tí a bá sì mọ̀ pé ó ń gbọ́ ohunkóhun tí a bá béèrè, a mọ̀ pé a máa rí àwọn ohun tí a béèrè gbà, torí pé a béèrè lọ́wọ́ rẹ̀.+

16 Tí ẹnikẹ́ni bá rí arákùnrin rẹ̀ tó ń dẹ́ṣẹ̀ tí kò yẹ fún ikú, ó máa gbàdúrà, Ọlọ́run sì máa fún un ní ìyè,+ àní, fún àwọn tí kò dẹ́ṣẹ̀ tó yẹ fún ikú. Ẹ̀ṣẹ̀ kan wà tó yẹ fún ikú.+ Irú ẹ̀ṣẹ̀ yẹn ni mi ò sọ fún un pé kó gbàdúrà nípa rẹ̀. 17 Gbogbo àìṣòdodo jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀,+ síbẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀ kan wà tí kò yẹ fún ikú.

18 A mọ̀ pé gbogbo ẹni tí a ti bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run kì í sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà, àmọ́ ẹni tí a bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run* ń ṣọ́ ọ, ẹni burúkú náà ò sì lè rí i mú.*+ 19 A mọ̀ pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run la ti wá, àmọ́ gbogbo ayé wà lábẹ́ agbára ẹni burúkú náà.+ 20 Ṣùgbọ́n a mọ̀ pé Ọmọ Ọlọ́run ti wá,+ ó sì ti jẹ́ ká ní òye* ká lè mọ ẹni tòótọ́ náà. A sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ẹni tòótọ́ náà,+ nípasẹ̀ Jésù Kristi Ọmọ rẹ̀. Èyí ni Ọlọ́run tòótọ́ náà àti ìyè àìnípẹ̀kun.+ 21 Ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, ẹ máa yẹra fún àwọn òrìṣà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́