ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kíróníkà

      • Àwọn àtọmọdọ́mọ Dáfídì (1-9)

      • Àwọn ọmọ tó wá láti ìdílé ọba Dáfídì (10-24)

1 Kíróníkà 3:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 3:2-5
  • +2Sa 13:32
  • +1Sa 25:43
  • +1Sa 25:2, 39

1 Kíróníkà 3:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 13:28, 37; 15:10; 18:14
  • +1Ọb 1:5, 11; 2:24

1 Kíróníkà 3:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 5:5

1 Kíróníkà 3:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 5:13-16; 1Kr 14:3-7
  • +Lk 3:23, 31
  • +Mt 1:7
  • +2Sa 11:3, 27

1 Kíróníkà 3:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìyàwó onípò kejì.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Wáhàrì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 13:1

1 Kíróníkà 3:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ọ̀rọ̀ yìí ní Hébérù lè túmọ̀ sí ọmọ, ọmọ ọmọ tàbí àtọmọdọ́mọ.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 11:43
  • +2Kr 13:1
  • +2Kr 14:1
  • +2Kr 20:31

1 Kíróníkà 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 21:5
  • +2Kr 22:2
  • +2Kr 24:1

1 Kíróníkà 3:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 25:1
  • +2Ọb 14:21
  • +2Kr 27:1

1 Kíróníkà 3:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 28:1
  • +2Kr 29:1
  • +2Ọb 21:1

1 Kíróníkà 3:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 21:19
  • +2Ọb 22:1

1 Kíróníkà 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 23:34; 2Kr 36:5
  • +2Ọb 24:17; 2Kr 36:11

1 Kíróníkà 3:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Àwọn ọmọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 24:6, 8; 25:27; Ẹst 2:6

1 Kíróníkà 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2005, ojú ìwé 9

    7/15/1992, ojú ìwé 5-6

1 Kíróníkà 3:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 5:2; Mt 1:12; Lk 3:23, 27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2005, ojú ìwé 9

1 Kíróníkà 3:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ.”

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ.”

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ.”

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ.”

1 Kíróníkà 3:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ.”

Àwọn míì

1 Kíró. 3:12Sa 3:2-5
1 Kíró. 3:12Sa 13:32
1 Kíró. 3:11Sa 25:43
1 Kíró. 3:11Sa 25:2, 39
1 Kíró. 3:22Sa 13:28, 37; 15:10; 18:14
1 Kíró. 3:21Ọb 1:5, 11; 2:24
1 Kíró. 3:42Sa 5:5
1 Kíró. 3:52Sa 5:13-16; 1Kr 14:3-7
1 Kíró. 3:5Lk 3:23, 31
1 Kíró. 3:5Mt 1:7
1 Kíró. 3:52Sa 11:3, 27
1 Kíró. 3:92Sa 13:1
1 Kíró. 3:101Ọb 11:43
1 Kíró. 3:102Kr 13:1
1 Kíró. 3:102Kr 14:1
1 Kíró. 3:102Kr 20:31
1 Kíró. 3:112Kr 21:5
1 Kíró. 3:112Kr 22:2
1 Kíró. 3:112Kr 24:1
1 Kíró. 3:122Kr 25:1
1 Kíró. 3:122Ọb 14:21
1 Kíró. 3:122Kr 27:1
1 Kíró. 3:132Kr 28:1
1 Kíró. 3:132Kr 29:1
1 Kíró. 3:132Ọb 21:1
1 Kíró. 3:142Ọb 21:19
1 Kíró. 3:142Ọb 22:1
1 Kíró. 3:152Ọb 23:34; 2Kr 36:5
1 Kíró. 3:152Ọb 24:17; 2Kr 36:11
1 Kíró. 3:162Ọb 24:6, 8; 25:27; Ẹst 2:6
1 Kíró. 3:19Ẹsr 5:2; Mt 1:12; Lk 3:23, 27
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kíróníkà 3:1-24

Kíróníkà Kìíní

3 Àwọn ọmọkùnrin tí wọ́n bí fún Dáfídì ní Hébúrónì+ nìyí: Ámínónì+ àkọ́bí, ìyá rẹ̀ ni Áhínóámù+ ará Jésírẹ́lì; ìkejì ni Dáníẹ́lì, ìyá rẹ̀ ni Ábígẹ́lì+ ará Kámẹ́lì; 2 ìkẹta ni Ábúsálómù+ ọmọ Máákà ọmọbìnrin Tálímáì ọba Géṣúrì; ìkẹrin ni Ádóníjà+ ọmọ Hágítì; 3 ìkarùn-ún ni Ṣẹfatáyà, ìyá rẹ̀ ni Ábítálì; ìkẹfà sì ni Ítíréámù, ìyá rẹ̀ ní Ẹ́gílà ìyàwó Dáfídì. 4 Àwọn mẹ́fà yìí ni wọ́n bí fún un ní Hébúrónì; ọdún méje àti oṣù mẹ́fà ló fi jọba níbẹ̀, ó sì fi ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) jọba ní Jerúsálẹ́mù.+

5 Àwọn tí wọ́n bí fún un ní Jerúsálẹ́mù+ nìyí: Ṣíméà, Ṣóbábù, Nátánì+ àti Sólómọ́nì;+ ìyá àwọn mẹ́rin yìí ni Bátí-ṣébà+ ọmọbìnrin Ámíélì. 6 Àwọn ọmọ mẹ́sàn-án míì ni Íbárì, Élíṣámà, Élífélétì, 7 Nógà, Néfégì, Jáfíà, 8 Élíṣámà, Élíádà àti Élífélétì. 9 Gbogbo àwọn yìí ni ọmọ Dáfídì, yàtọ̀ sí àwọn ọmọ àwọn wáhàrì,* Támárì+ sì ni arábìnrin wọn.

10 Ọmọ Sólómọ́nì ni Rèhóbóámù;+ ọmọ* rẹ̀ ni Ábíjà,+ ọmọ rẹ̀ ni Ásà,+ ọmọ rẹ̀ ni Jèhóṣáfátì,+ 11 ọmọ rẹ̀ ni Jèhórámù,+ ọmọ rẹ̀ ni Ahasáyà,+ ọmọ rẹ̀ ni Jèhóáṣì,+ 12 ọmọ rẹ̀ ni Amasááyà,+ ọmọ rẹ̀ ni Asaráyà,+ ọmọ rẹ̀ ni Jótámù,+ 13 ọmọ rẹ̀ ni Áhásì,+ ọmọ rẹ̀ ni Hẹsikáyà,+ ọmọ rẹ̀ ni Mánásè,+ 14 ọmọ rẹ̀ ni Ámọ́nì,+ ọmọ rẹ̀ ni Jòsáyà.+ 15 Àwọn ọmọ Jòsáyà ni Jóhánánì àkọ́bí, ìkejì ni Jèhóákímù,+ ìkẹta ni Sedekáyà,+ ìkẹrin ni Ṣálúmù. 16 Ọmọ* Jèhóákímù ni Jekonáyà,+ Sedekáyà sì ni ọmọ rẹ̀. 17 Àwọn ọmọ Jekonáyà ẹlẹ́wọ̀n ni Ṣéálítíẹ́lì, 18 Málíkírámù, Pedáyà, Ṣẹ́násà, Jekamáyà, Hóṣámà àti Nedabáyà. 19 Àwọn ọmọ Pedáyà ni Serubábélì+ àti Ṣíméì; àwọn ọmọ Serubábélì sì ni Méṣúlámù àti Hananáyà (Ṣẹ́lómítì ni arábìnrin wọn); 20 àwọn ọmọ márùn-ún míì ni Háṣúbà, Óhélì, Berekáyà, Hasadáyà àti Juṣabi-hésédì. 21 Àwọn ọmọ Hananáyà ni Pẹlatáyà àti Jeṣáyà; ọmọ* Jeṣáyà ni Refáyà; ọmọ* Refáyà ni Áánánì; ọmọ* Áánánì ni Ọbadáyà; ọmọ* Ọbadáyà ni Ṣẹkanáyà; 22 ọmọ* Ṣẹkanáyà ni Ṣemáyà, àwọn ọmọ Ṣemáyà sì ni: Hátúṣì, Ígálì, Baráyà, Nearáyà àti Ṣáfátì, gbogbo wọn jẹ́ mẹ́fà. 23 Àwọn ọmọ Nearáyà ni Élíóénáì, Hisikáyà àti Ásíríkámù, àwọn mẹ́ta. 24 Àwọn ọmọ Élíóénáì sì ni Hodafáyà, Élíáṣíbù, Pẹláyà, Ákúbù, Jóhánánì, Deláyà àti Ánáánì, àwọn méje.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́