ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jémíìsì 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jémíìsì

      • Ẹ má ṣe jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé (1-12)

        • Ẹ dojú ìjà kọ Èṣù (7)

        • Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run (8)

      • Ìkìlọ̀ pé ká má ṣe gbéra ga (13-17)

        • “Tí Jèhófà bá fẹ́” (15)

Jémíìsì 4:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “tó ń bá ẹ̀yà ara yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 7:23; Ga 5:17; Jem 3:14; 1Pe 2:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1998, ojú ìwé 12

    11/15/1997, ojú ìwé 19

    9/15/1995, ojú ìwé 4

Jémíìsì 4:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 5:22; Jem 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1998, ojú ìwé 12

    11/15/1997, ojú ìwé 19

    9/15/1995, ojú ìwé 4

Jémíìsì 4:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2021 ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/1998, ojú ìwé 12

    11/15/1997, ojú ìwé 19

Jémíìsì 4:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aláìṣòótọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 19:2; Jo 15:19; 17:14; 18:36; 1Jo 2:15; 5:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 48

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2000, ojú ìwé 5

    9/1/1998, ojú ìwé 11-12

    11/15/1997, ojú ìwé 19-20

Jémíìsì 4:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 6:5; 8:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 20

    8/1/2000, ojú ìwé 11

    9/1/1998, ojú ìwé 12-13

    11/15/1997, ojú ìwé 19-20

    9/15/1995, ojú ìwé 4-5, 15

Jémíìsì 4:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 138:6
  • +Owe 3:34; 1Pe 5:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/1999, ojú ìwé 6

    9/1/1998, ojú ìwé 12-13

    11/15/1997, ojú ìwé 19-20

Jémíìsì 4:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 12:9; 1Pe 2:17; 5:6
  • +Ef 4:27; 6:11
  • +Mt 4:10, 11; Lk 4:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 24

    Jí!,

    10/2010, ojú ìwé 23

    9/8/1998, ojú ìwé 24-25

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 27-31

    1/15/2006, ojú ìwé 30

    11/15/1997, ojú ìwé 20

    2/1/1993, ojú ìwé 14-19

Jémíìsì 4:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 44:22; 55:6, 7
  • +Ais 1:16
  • +1Jo 3:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 4

    A Ṣètò Wa, ojú ìwé 169

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2015, ojú ìwé 14

    4/15/2015, ojú ìwé 19-23

    5/1/2004, ojú ìwé 14-15

    7/1/2003, ojú ìwé 9-10

    12/15/2002, ojú ìwé 8-18

    11/15/1997, ojú ìwé 20

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 16-25, 310-319

    Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, ojú ìwé 290

Jémíìsì 4:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 2:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 20

Jémíìsì 4:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 7:14; 33:12, 13
  • +Owe 29:23; Mt 23:12

Jémíìsì 4:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:16; Owe 17:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 20-21

Jémíìsì 4:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 33:22
  • +Mt 10:28
  • +Mt 7:1; Lk 6:37; Ro 14:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 21

Jémíìsì 4:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 12:18-20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 21

Jémíìsì 4:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 39:6; Owe 27:1; Onw 6:12
  • +Job 14:1, 2; Sm 102:3; 1Pe 1:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 3 2021 ojú ìwé 11

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 21

Jémíìsì 4:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 18:21; Heb 6:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 21

Jémíìsì 4:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2005, ojú ìwé 13

    11/15/1997, ojú ìwé 21

Jémíìsì 4:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 12:47; Jo 9:41; 15:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 21

    9/15/1996, ojú ìwé 17

Àwọn míì

Jém. 4:1Ro 7:23; Ga 5:17; Jem 3:14; 1Pe 2:11
Jém. 4:2Mt 5:22; Jem 3:16
Jém. 4:42Kr 19:2; Jo 15:19; 17:14; 18:36; 1Jo 2:15; 5:19
Jém. 4:5Jẹ 6:5; 8:21
Jém. 4:6Sm 138:6
Jém. 4:6Owe 3:34; 1Pe 5:5
Jém. 4:7Heb 12:9; 1Pe 2:17; 5:6
Jém. 4:7Ef 4:27; 6:11
Jém. 4:7Mt 4:10, 11; Lk 4:13
Jém. 4:8Ais 44:22; 55:6, 7
Jém. 4:8Ais 1:16
Jém. 4:81Jo 3:3
Jém. 4:9Joẹ 2:12
Jém. 4:102Kr 7:14; 33:12, 13
Jém. 4:10Owe 29:23; Mt 23:12
Jém. 4:11Le 19:16; Owe 17:9
Jém. 4:12Ais 33:22
Jém. 4:12Mt 10:28
Jém. 4:12Mt 7:1; Lk 6:37; Ro 14:4
Jém. 4:13Lk 12:18-20
Jém. 4:14Sm 39:6; Owe 27:1; Onw 6:12
Jém. 4:14Job 14:1, 2; Sm 102:3; 1Pe 1:24
Jém. 4:15Iṣe 18:21; Heb 6:3
Jém. 4:17Lk 12:47; Jo 9:41; 15:22
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jémíìsì 4:1-17

Lẹ́tà Jémíìsì

4 Ibo ni ogun àti àwọn ìjà tó wà láàárín yín ti wá? Ṣebí inú ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara tó ń bá yín* fínra ló ti wá?+ 2 Ó ń wù yín, síbẹ̀ ẹ ò ní in. Ẹ̀ ń pààyàn, ẹ ò sì yéé ṣojúkòkòrò, síbẹ̀ ọwọ́ yín ò tẹ̀ ẹ́. Ẹ̀ ń jà, ẹ sì ń jagun.+ Ẹ ò ní torí pé ẹ ò béèrè. 3 Nígbà tí ẹ sì béèrè, ẹ ò rí gbà torí ohun tí kò dáa lẹ fẹ́ fi ṣe, ṣe lẹ fẹ́ lò ó fún ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara yín.

4 Ẹ̀yin alágbèrè,* ṣé ẹ ò mọ̀ pé bíbá ayé ṣọ̀rẹ́ ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run ni? Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé ń sọ ara rẹ̀ di ọ̀tá Ọlọ́run.+ 5 Àbí ẹ rò pé lásán ni ìwé mímọ́ sọ pé: “Ẹ̀mí tó ń gbé inú wa ń mú ká máa jowú ṣáá”?+ 6 Àmọ́ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí Ó ń fi hàn tóbi ju èyí lọ. Ìdí nìyẹn tí ìwé mímọ́ fi sọ pé: “Ọlọ́run dojú ìjà kọ àwọn agbéraga,+ àmọ́ ó ń fi inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí hàn sí àwọn onírẹ̀lẹ̀.”+

7 Torí náà, ẹ fi ara yín sábẹ́ Ọlọ́run;+ àmọ́ ẹ dojú ìjà kọ Èṣù,+ ó sì máa sá kúrò lọ́dọ̀ yín.+ 8 Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run, á sì sún mọ́ yín.+ Ẹ wẹ ọwọ́ yín mọ́, ẹ̀yin ẹlẹ́ṣẹ̀,+ kí ẹ sì wẹ ọkàn yín mọ́,+ ẹ̀yin aláìnípinnu. 9 Ẹ banú jẹ́, ẹ ṣọ̀fọ̀, kí ẹ sì sunkún.+ Kí ẹ̀rín yín di ọ̀fọ̀, kí ayọ̀ yín sì di ìbànújẹ́. 10 Ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ ní ojú Jèhófà,*+ ó sì máa gbé yín ga.+

11 Ẹ̀yin ará, ẹ má sọ̀rọ̀ tí kò dáa nípa ara yín mọ́.+ Ẹnikẹ́ni tó bá ń sọ̀rọ̀ tí kò dáa nípa arákùnrin kan tàbí tó ń dá arákùnrin rẹ̀ lẹ́jọ́, ó ń sọ̀rọ̀ tí kò dáa nípa òfin, ó sì ń dá òfin lẹ́jọ́. Tí o bá wá ń dá òfin lẹ́jọ́, o ò pa òfin mọ́, kàkà bẹ́ẹ̀ onídàájọ́ ni ọ́. 12 Ẹnì kan ṣoṣo ni Afúnnilófin àti Onídàájọ́ wa,+ ẹni tó lè gbà là, tó sì lè pa run.+ Àmọ́ ìwọ, ta ni ọ́ tí o fi ń dá ọmọnìkejì rẹ lẹ́jọ́?+

13 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sọ pé: “Lónìí tàbí lọ́la, a máa rìnrìn àjò lọ sí ìlú yìí, a máa lo ọdún kan níbẹ̀, a máa ṣòwò, a sì máa jèrè,”+ 14 bẹ́ẹ̀ sì rèé, ẹ ò mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí yín lọ́la.+ Torí ìkùukùu ni yín, tó máa ń wà fúngbà díẹ̀, lẹ́yìn náà tí á pòórá.+ 15 Kàkà bẹ́ẹ̀, ó yẹ kí ẹ sọ pé: “Tí Jèhófà* bá fẹ́,+ a máa wà láàyè, a sì máa ṣe tibí tàbí tọ̀hún.” 16 Àmọ́ ẹ̀ ń gbéra ga, ẹ sì ń fọ́nnu. Gbogbo ìfọ́nnu bẹ́ẹ̀ burú. 17 Torí náà, tí ẹnì kan bá mọ bí a ṣe ń ṣe ohun tó tọ́, síbẹ̀ tí kò ṣe é, ẹ̀ṣẹ̀ ni.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́