ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ìran nípa Jèhófà nínú tẹ́ńpìlì rẹ̀ (1-4)

        • “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà” (3)

      • A wẹ ètè Àìsáyà mọ́ (5-7)

      • Àìsáyà gba iṣẹ́ (8-10)

        • “Èmi nìyí! Rán mi!” (8)

      • “Títí dìgbà wo, Jèhófà?” (11-13)

Àìsáyà 6:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 26:23
  • +1Ọb 22:19; Da 7:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 26

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2011, ojú ìwé 26

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 87-88

Àìsáyà 6:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Ó.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2011, ojú ìwé 26

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 88-89

Àìsáyà 6:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:11; Ifi 4:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2011, ojú ìwé 26

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 89-90

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 185-186

Àìsáyà 6:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Ohùn ẹni tó ń sọ̀rọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 15:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 90

Àìsáyà 6:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “A ti pa mí lẹ́nu mọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 29:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 32-34

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 90-92

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    4/1/1991, ojú ìwé 22-23

Àìsáyà 6:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 10:2
  • +Ifi 8:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 92-93

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    4/1/1991, ojú ìwé 23

Àìsáyà 6:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 92-93

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    4/1/1991, ojú ìwé 23

Àìsáyà 6:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:26; Jo 1:1, 2; 12:41
  • +Sm 110:3; Mt 4:19, 20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2012, ojú ìwé 29-30

    12/1/2006, ojú ìwé 9

    6/15/1998, ojú ìwé 24

    4/1/1991, ojú ìwé 23

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 93-95, 98-100

Àìsáyà 6:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 5:21; Mt 13:14; Lk 8:9, 10; Iṣe 28:25, 26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 95-96

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    9/15/1994, ojú ìwé 17

Àìsáyà 6:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 3:7
  • +Jer 6:10; Jo 3:20
  • +Mt 13:15; Iṣe 28:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jésù—Ọ̀nà, ojú ìwé 242

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 95-96, 99-100

Àìsáyà 6:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:20, 21; Ais 3:26; 24:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2006, ojú ìwé 9

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 96-97, 99-100

Àìsáyà 6:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 25:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 96-97

Àìsáyà 6:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “igi óákù.”

  • *

    Tàbí “ọmọ.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 97-98, 99-100

Àwọn míì

Àìsá. 6:12Kr 26:23
Àìsá. 6:11Ọb 22:19; Da 7:9
Àìsá. 6:3Ẹk 15:11; Ifi 4:8
Àìsá. 6:4Ifi 15:8
Àìsá. 6:5Ais 29:13
Àìsá. 6:6Isk 10:2
Àìsá. 6:6Ifi 8:5
Àìsá. 6:8Jẹ 1:26; Jo 1:1, 2; 12:41
Àìsá. 6:8Sm 110:3; Mt 4:19, 20
Àìsá. 6:9Jer 5:21; Mt 13:14; Lk 8:9, 10; Iṣe 28:25, 26
Àìsá. 6:10Isk 3:7
Àìsá. 6:10Jer 6:10; Jo 3:20
Àìsá. 6:10Mt 13:15; Iṣe 28:27
Àìsá. 6:112Kr 36:20, 21; Ais 3:26; 24:1
Àìsá. 6:122Ọb 25:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 6:1-13

Àìsáyà

6 Ní ọdún tí Ọba Ùsáyà kú,+ mo rí Jèhófà tó jókòó sórí ìtẹ́ gíga, tó sì ta yọ,+ etí aṣọ rẹ̀ kún inú tẹ́ńpìlì. 2 Àwọn séráfù dúró lókè rẹ̀; ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìyẹ́ mẹ́fà. Ọ̀kọ̀ọ̀kan* fi méjì bo ojú, ó fi méjì bo ẹsẹ̀, ọ̀kọ̀ọ̀kan sì ń fi méjì fò kiri.

 3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé:

“Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+

Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.”

4 Igbe náà* mú kí ojú ibi tí ilẹ̀kùn ti ń yí mì tìtì, èéfín sì kún ilé náà.+

 5 Mo wá sọ pé: “Mo gbé!

Mo ti kú tán,*

Torí ọkùnrin tí ètè rẹ̀ kò mọ́ ni mí,

Àárín àwọn èèyàn tí ètè wọn ò mọ́ ni mo sì ń gbé;+

Torí ojú mi ti rí Ọba, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun fúnra rẹ̀!”

6 Ni ọ̀kan lára àwọn séráfù náà bá fò wá sọ́dọ̀ mi, ẹyin iná tó pọ́n yòò+ tó fi ẹ̀mú mú látorí pẹpẹ + sì wà ní ọwọ́ rẹ̀. 7 Ó fi kan ẹnu mi, ó sì sọ pé:

“Wò ó! Ó ti kan ètè rẹ.

Ẹ̀bi rẹ ti kúrò,

A sì ti ṣe ètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.”

8 Mo wá gbọ́ ohùn Jèhófà tó sọ pé: “Ta ni kí n rán, ta ló sì máa lọ fún wa?”+ Mo sọ pé: “Èmi nìyí! Rán mi!”+

 9 Ó fèsì pé: “Lọ, kí o sì sọ fún àwọn èèyàn yìí pé:

‘Ẹ máa gbọ́ léraléra,

Àmọ́ kò ní yé yín;

Ẹ máa rí léraléra,

Àmọ́ ẹ ò ní mọ nǹkan kan.’+

10 Mú kí ọkàn àwọn èèyàn yìí yigbì,+

Mú kí etí wọn di,+

Kí o sì lẹ ojú wọn pọ̀,

Kí wọ́n má bàa fi ojú wọn ríran,

Kí wọ́n má sì fi etí wọn gbọ́rọ̀,

Kí ọkàn wọn má bàa lóye,

Kí wọ́n má bàa yí pa dà, kí wọ́n sì rí ìwòsàn.”+

11 Ni mo bá sọ pé: “Títí dìgbà wo, Jèhófà?” Ó dáhùn pé:

“Títí àwọn ìlú náà fi máa fọ́ túútúú, tí kò sì ní sẹ́ni tó ń gbé ibẹ̀,

Tí kò ní sẹ́nì kankan nínú àwọn ilé,

Títí ilẹ̀ náà fi máa pa run, tó sì máa di ahoro;+

12 Títí Jèhófà fi máa mú àwọn èèyàn jìnnà,+

Tí gbogbo ilẹ̀ náà á sì di ahoro.

13 “Àmọ́ ìdá mẹ́wàá ṣì máa wà níbẹ̀, wọ́n á sì tún dáná sun ún, bí igi ńlá àti igi ràgàjì,* tí kùkùté rẹ̀ máa ń ṣẹ́ kù lẹ́yìn tí wọ́n bá gé e; irúgbìn* mímọ́ ló máa jẹ́ kùkùté rẹ̀.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́