ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 148
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Kí gbogbo ẹ̀dá máa yin Jèhófà

        • “Ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin áńgẹ́lì rẹ̀” (2)

        • ‘Ẹ yìn ín, oòrùn, òṣùpá àti ìràwọ̀’ (3)

        • Kí àwọn ọ̀dọ́ àti àwọn arúgbó máa yin Ọlọ́run (12, 13)

Sáàmù 148:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 89:5

Sáàmù 148:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 103:20; Lk 2:13
  • +Jer 32:18; Jud 14

Sáàmù 148:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 19:1

Sáàmù 148:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọ̀run àwọn ọ̀run.”

Sáàmù 148:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 33:6

Sáàmù 148:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 89:37
  • +Sm 119:91; Jer 31:35, 36; 33:25

Sáàmù 148:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 54-55

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2004, ojú ìwé 12-13

Sáàmù 148:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 9:23; Sm 107:25; Ais 30:30

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2004, ojú ìwé 13

Sáàmù 148:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 98:8
  • +1Kr 16:33; Ais 44:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2004, ojú ìwé 13

Sáàmù 148:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2004, ojú ìwé 13-14

Sáàmù 148:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 2:10, 11

Sáàmù 148:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “wúńdíá.”

  • *

    Tàbí “arúgbó àti ọ̀dọ́.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 20

Sáàmù 148:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 8:1; Ais 12:4
  • +1Ọb 8:27; 1Kr 29:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 20

Sáàmù 148:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìwo.”

  • *

    Tàbí “Halelúyà!” “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Àwọn míì

Sm 148:1Sm 89:5
Sm 148:2Sm 103:20; Lk 2:13
Sm 148:2Jer 32:18; Jud 14
Sm 148:3Sm 19:1
Sm 148:5Sm 33:6
Sm 148:6Sm 89:37
Sm 148:6Sm 119:91; Jer 31:35, 36; 33:25
Sm 148:8Ẹk 9:23; Sm 107:25; Ais 30:30
Sm 148:9Sm 98:8
Sm 148:91Kr 16:33; Ais 44:23
Sm 148:10Ais 43:20
Sm 148:11Sm 2:10, 11
Sm 148:13Sm 8:1; Ais 12:4
Sm 148:131Ọb 8:27; 1Kr 29:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 148:1-14

Sáàmù

148 Ẹ yin Jáà!*

Ẹ yin Jèhófà láti ọ̀run;+

Ẹ yìn ín ní àwọn ibi gíga.

2 Ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin áńgẹ́lì rẹ̀.+

Ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin ọmọ ogun rẹ̀.+

3 Ẹ yìn ín, oòrùn àti òṣùpá.

Ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin ìràwọ̀ tó ń tàn.+

4 Ẹ yìn ín, ẹ̀yin ọ̀run gíga jù lọ*

Àti ẹ̀yin omi tó wà lókè àwọn ọ̀run.

5 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,

Nítorí ó pàṣẹ, a sì dá wọn.+

6 Ó fìdí wọn múlẹ̀ kí wọ́n lè wà títí láé àti láéláé;+

Ó pa àṣẹ tí kò ní kọjá lọ.+

7 Ẹ yin Jèhófà láti ayé,

Ẹ̀yin ẹ̀dá ńlá inú òkun àti gbogbo ẹ̀yin ibú omi,

8 Ẹ̀yin mànàmáná àti yìnyín ńlá, yìnyín kéékèèké àti ojú ọ̀run tó ṣú bolẹ̀,

Ìwọ ìjì líle, tó ń mú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ,+

9 Ẹ̀yin òkè ńlá àti gbogbo ẹ̀yin òkè kéékèèké,+

Ẹ̀yin igi eléso àti gbogbo ẹ̀yin igi kédárì,+

10 Ẹ̀yin ẹranko igbó+ àti gbogbo ẹ̀yin ẹran ọ̀sìn,

Ẹ̀yin ohun tó ń rákò àti ẹ̀yin ẹyẹ abìyẹ́,

11 Ẹ̀yin ọba ayé àti gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,

Ẹ̀yin olórí àti gbogbo ẹ̀yin onídàájọ́ ayé,+

12 Ẹ̀yin ọ̀dọ́kùnrin àti ẹ̀yin ọ̀dọ́bìnrin,*

Ẹ̀yin àgbà ọkùnrin àti ẹ̀yin ọ̀dọ́.*

13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,

Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+

Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+

14 Yóò gbé agbára* àwọn èèyàn rẹ̀ ga,

Ìyìn gbogbo àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀,

Ti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn tó sún mọ́ ọn.

Ẹ yin Jáà!*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́