ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sekaráyà 6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sekaráyà

      • Ìran 8: Kẹ̀kẹ́ ẹṣin mẹ́rin (1-8)

      • Èéhù yóò di ọba àti àlùfáà (9-15)

Sekaráyà 6:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 27-28

Sekaráyà 6:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 6:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 27

Sekaráyà 6:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 6:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 27

Sekaráyà 6:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 104:4
  • +2Kr 18:18; Job 1:6; Da 7:10; Lk 1:19; Heb 1:7, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 28

Sekaráyà 6:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, kẹ̀kẹ́ ẹṣin.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 2:6, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 28

Sekaráyà 6:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 28

Sekaráyà 6:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 28

Sekaráyà 6:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “adé ńlá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Hag 1:1; Sek 3:3, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 28-29

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2007, ojú ìwé 10

Sekaráyà 6:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:1; Sek 3:8
  • +Sek 8:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 29

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2007, ojú ìwé 10

    4/15/2006, ojú ìwé 26

Sekaráyà 6:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ipò rẹ̀ bí alákòóso àti àlùfáà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 3:1; 4:14; 8:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 29

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2007, ojú ìwé 10

    4/15/2006, ojú ìwé 26

Sekaráyà 6:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Adé ńlá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 6:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 30

Sekaráyà 6:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 29-30

Àwọn míì

Sek. 6:2Sek 6:6
Sek. 6:3Sek 6:7
Sek. 6:5Sm 104:4
Sek. 6:52Kr 18:18; Job 1:6; Da 7:10; Lk 1:19; Heb 1:7, 14
Sek. 6:6Sek 2:6, 7
Sek. 6:11Hag 1:1; Sek 3:3, 5
Sek. 6:12Ais 11:1; Sek 3:8
Sek. 6:12Sek 8:9
Sek. 6:13Heb 3:1; 4:14; 8:1
Sek. 6:14Sek 6:10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sekaráyà 6:1-15

Sekaráyà

6 Mo tún wòkè, mo sì rí kẹ̀kẹ́ ẹṣin mẹ́rin tó ń bọ̀ láti àárín òkè méjì, òkè bàbà sì ni àwọn òkè náà. 2 Àwọn ẹṣin pupa ló ń fa kẹ̀kẹ́ àkọ́kọ́, àwọn ẹṣin dúdú ló sì ń fa kẹ̀kẹ́ kejì.+ 3 Àwọn ẹṣin funfun ló ń fa kẹ̀kẹ́ kẹta, àwọn ẹṣin aláwọ̀ tó-tò-tó àti kàlákìnní ló sì ń fa kẹ̀kẹ́ kẹrin.+

4 Mo bi áńgẹ́lì tó ń bá mi sọ̀rọ̀ pé: “Kí làwọn nǹkan yìí, olúwa mi?”

5 Áńgẹ́lì náà dá mi lóhùn pé: “Ìwọ̀nyí ni àwọn ẹ̀mí+ mẹ́rin ti ọ̀run tó ń jáde lọ lẹ́yìn tí wọ́n dúró níwájú Olúwa gbogbo ayé.+ 6 Èyí* tí àwọn ẹṣin dúdú ń fà jáde lọ sí ilẹ̀ àríwá;+ èyí tí àwọn ẹṣin funfun ń fà lọ sí ìkọjá òkun; àwọn aláwọ̀ tó-tò-tó sì ń lọ sí ilẹ̀ gúúsù. 7 Ara sì ń yá àwọn ẹṣin aláwọ̀ kàlákìnní náà láti jáde lọ kí wọ́n lè rìn káàkiri ayé.” Áńgẹ́lì náà wá sọ pé: “Ẹ lọ, ẹ rìn káàkiri ayé.” Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í rìn káàkiri ayé.

8 Ó wá pè mí, ó sì sọ pé: “Wò ó, àwọn tó ń jáde lọ sí ilẹ̀ àríwá ti rọ ẹ̀mí Jèhófà lójú ní ilẹ̀ náà.”

9 Jèhófà tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 10 “Gba ohun tí Hélídáì, Tóbíjà àti Jedáyà mú wá láti ọ̀dọ̀ àwọn tí wọ́n kó nígbèkùn; ní ọjọ́ yẹn, kí ìwọ àti àwọn èèyàn yìí tó wá láti Bábílónì lọ sí ilé Jòsáyà ọmọ Sefanáyà. 11 Kí o fi fàdákà àti wúrà ṣe adé,* kí o sì fi dé orí Àlùfáà Àgbà Jóṣúà+ ọmọ Jèhósádákì. 12 Kí o sì sọ fún un pé,

“‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Èéhù+ rèé. Yóò hù jáde láti àyè rẹ̀, yóò sì kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà.+ 13 Òun ni yóò kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà, òun ni iyì máa tọ́ sí. Yóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀, yóò sì ṣàkóso, yóò sì tún jẹ́ àlùfáà lórí ìtẹ́ rẹ̀,+ ọ̀kan kò sì ní pa èkejì lára.* 14 Adé* náà yóò jẹ́ ohun ìrántí fún Hélémù, Tóbíjà, Jedáyà+ àti Hénì ọmọ Sefanáyà nínú tẹ́ńpìlì Jèhófà. 15 Àwọn tó wà lọ́nà jíjìn yóò wá, wọ́n sì máa wà lára àwọn tí yóò kọ́ tẹ́ńpìlì Jèhófà.” Ẹ ó sì mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló rán mi sí yín. Yóò sì rí bẹ́ẹ̀, tí ẹ bá fetí sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run yín.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́