ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Tímótì 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Tímótì

      • “Ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ láìkù síbì kan” (1-5)

        • Wàásù ọ̀rọ̀ náà láìfi falẹ̀ (2)

      • “Mo ti ja ìjà rere náà” (6-8)

      • Àwọn ọ̀rọ̀ ara ẹni (9-18)

      • Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (19-22)

2 Tímótì 4:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 5:22; Iṣe 17:31; 2Kọ 5:10
  • +Jo 5:28, 29; Iṣe 10:42
  • +1Ti 6:14, 15; 1Pe 5:4
  • +Ifi 11:15; 12:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    4/2010, ojú ìwé 10-11

2 Tímótì 4:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “kí o sì máa lo ọnà ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 2:15
  • +1Ti 5:20; Tit 1:7, 9, 13; 2:15
  • +2Ti 2:24, 25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 165

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 15

    1/15/2008, ojú ìwé 8-9

    1/1/2003, ojú ìwé 29-30

    3/15/1999, ojú ìwé 10

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 266-267

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    2/2000, ojú ìwé 1

2 Tímótì 4:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ṣeni lóore; tó wúlò.”

  • *

    Ní Grk., “kí wọ́n lè máa rin wọ́n ní etí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 1:9, 10
  • +1Ti 4:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2012, ojú ìwé 15

    7/1/2005, ojú ìwé 5-6

2 Tímótì 4:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2011, ojú ìwé 17-18

    9/15/2002, ojú ìwé 17-19

    4/1/1994, ojú ìwé 29-31

2 Tímótì 4:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “máa wàásù ìhìn rere náà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 1:8; 2:3
  • +Ro 15:19; Kol 1:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2019, ojú ìwé 2-7

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2009, ojú ìwé 16-17

    3/15/2004, ojú ìwé 10, 15

    12/1/1995, ojú ìwé 8

2 Tímótì 4:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 28:6, 7
  • +Flp 1:23

2 Tímótì 4:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 9:26; 1Ti 6:12
  • +Flp 3:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 276-277

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/1999, ojú ìwé 17

2 Tímótì 4:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 9:25; Jem 1:12
  • +Jo 5:22
  • +1Pe 5:4; Ifi 2:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 276-277

2 Tímótì 4:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2015, ojú ìwé 15

    5/15/2004, ojú ìwé 19-20

2 Tímótì 4:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àsìkò yìí.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 4:14; Flm 23, 24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 10-11

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2015, ojú ìwé 16

    11/15/1998, ojú ìwé 31

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 12

2 Tímótì 4:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2010, ojú ìwé 8-9

    11/15/2007, ojú ìwé 18

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 118

2 Tímótì 4:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 6:21; Kol 4:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1998, ojú ìwé 8

2 Tímótì 4:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, àwọn àkájọ ìwé tí wọ́n fi awọ ṣe.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2011, ojú ìwé 18-19

    9/15/2008, ojú ìwé 31

    5/15/2008, ojú ìwé 22

    4/1/1998, ojú ìwé 11

2 Tímótì 4:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 28:4; 62:12; Owe 24:12

2 Tímótì 4:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2015, ojú ìwé 24-25

2 Tímótì 4:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 9:15
  • +Sm 22:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2015, ojú ìwé 24-26, 28

2 Tímótì 4:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 20:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2015, ojú ìwé 25

2 Tímótì 4:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 16:3
  • +2Ti 1:16

2 Tímótì 4:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 19:22
  • +Iṣe 21:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2015, ojú ìwé 25

2 Tímótì 4:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2012, ojú ìwé 12-13

    2/1/1994, ojú ìwé 17

Àwọn míì

2 Tím. 4:1Jo 5:22; Iṣe 17:31; 2Kọ 5:10
2 Tím. 4:1Jo 5:28, 29; Iṣe 10:42
2 Tím. 4:11Ti 6:14, 15; 1Pe 5:4
2 Tím. 4:1Ifi 11:15; 12:10
2 Tím. 4:22Ti 2:15
2 Tím. 4:21Ti 5:20; Tit 1:7, 9, 13; 2:15
2 Tím. 4:22Ti 2:24, 25
2 Tím. 4:31Ti 1:9, 10
2 Tím. 4:31Ti 4:1
2 Tím. 4:52Ti 1:8; 2:3
2 Tím. 4:5Ro 15:19; Kol 1:25
2 Tím. 4:6Nọ 28:6, 7
2 Tím. 4:6Flp 1:23
2 Tím. 4:71Kọ 9:26; 1Ti 6:12
2 Tím. 4:7Flp 3:14
2 Tím. 4:81Kọ 9:25; Jem 1:12
2 Tím. 4:8Jo 5:22
2 Tím. 4:81Pe 5:4; Ifi 2:10
2 Tím. 4:10Kol 4:14; Flm 23, 24
2 Tím. 4:12Ef 6:21; Kol 4:7
2 Tím. 4:14Sm 28:4; 62:12; Owe 24:12
2 Tím. 4:17Iṣe 9:15
2 Tím. 4:17Sm 22:21
2 Tím. 4:18Ifi 20:4
2 Tím. 4:19Ro 16:3
2 Tím. 4:192Ti 1:16
2 Tím. 4:20Iṣe 19:22
2 Tím. 4:20Iṣe 21:29
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Tímótì 4:1-22

Ìwé Kejì sí Tímótì

4 Mo pàṣẹ tó rinlẹ̀ yìí fún ọ níwájú Ọlọ́run àti Kristi Jésù, ẹni tó máa ṣèdájọ́+ àwọn alààyè àti òkú,+ nípasẹ̀ ìfarahàn rẹ̀+ àti Ìjọba rẹ̀:+ 2 Wàásù ọ̀rọ̀ náà;+ máa ṣe bẹ́ẹ̀ láìfi falẹ̀ ní àkókò tó rọrùn àti ní àkókò tí kò rọrùn; máa báni wí,+ máa fi ìbáwí tọ́ni sọ́nà, máa gbani níyànjú, pẹ̀lú ọ̀pọ̀ sùúrù àti ọ̀nà ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ tó dáa.*+ 3 Torí ìgbà kan ń bọ̀ tí wọn ò ní tẹ̀ lé ẹ̀kọ́ tó ṣàǹfààní,*+ àmọ́ wọ́n á máa ṣe ìfẹ́ inú ara wọn, wọ́n á fi àwọn olùkọ́ yí ara wọn ká, kí wọ́n lè máa sọ ohun tí wọ́n fẹ́ gbọ́.*+ 4 Wọn ò ní fetí sí òtítọ́ mọ́, ìtàn èké ni wọ́n á máa fetí sí. 5 Àmọ́, kí ìwọ máa ronú bó ṣe tọ́ nínú ohun gbogbo, fara da ìnira,+ ṣe iṣẹ́ ajíhìnrere,* ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ láìkù síbì kan.+

6 Torí ní báyìí, a ti ń tú mi jáde bí ọrẹ ohun mímu,+ a sì máa tó tú mi sílẹ̀.+ 7 Mo ti ja ìjà rere náà,+ mo ti sá eré ìje náà dé ìparí,+ mo ti pa ìgbàgbọ́ mọ́. 8 Láti ìsinsìnyí lọ, a ti fi adé òdodo  + pa mọ́ dè mí, èyí tí Olúwa, onídàájọ́ òdodo,+ máa fi san mí lẹ́san ní ọjọ́ yẹn,+ síbẹ̀ kì í ṣe fún èmi nìkan, àmọ́ fún gbogbo àwọn tó nífẹ̀ẹ́ ìfarahàn rẹ̀.

9 Sa gbogbo ipá rẹ láti wá sọ́dọ̀ mi láìpẹ́. 10 Ìdí ni pé Démà+ ti pa mí tì torí ó nífẹ̀ẹ́ ètò àwọn nǹkan yìí,* ó sì ti lọ sí Tẹsalóníkà, Kírẹ́sẹ́ńsì ti lọ sí Gálátíà, Títù sì ti lọ sí Damatíà. 11 Lúùkù nìkan ló wà lọ́dọ̀ mi. Mú Máàkù dání tí o bá ń bọ̀, torí ó ń ràn mí lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́. 12 Àmọ́ mo ti rán Tíkíkù+ lọ sí Éfésù. 13 Tí o bá ń bọ̀, bá mi mú aṣọ àwọ̀lékè tí mo fi sílẹ̀ ní Tíróásì lọ́dọ̀ Kápọ́sì dání àti àwọn àkájọ ìwé, ní pàtàkì àwọn ìwé awọ.*

14 Alẹkisáńdà alágbẹ̀dẹ bàbà fi ojú mi rí màbo. Jèhófà* máa fi iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ san án lẹ́san.+ 15 Kí ìwọ náà máa ṣọ́ra fún un, torí ó ń ta ko ọ̀rọ̀ wa gan-an.

16 Nígbà tí mo kọ́kọ́ lọ jẹ́jọ́, ẹnì kankan ò wá gbèjà mi, ṣe ni gbogbo wọn pa mí tì—kí a má ṣe kà á sí wọn lọ́rùn. 17 Àmọ́ Olúwa dúró tì mí, ó sì fún mi lágbára, ká lè lò mí láti ṣe iṣẹ́ ìwàásù láìkù síbì kan, kí gbogbo orílẹ̀-èdè lè gbọ́ ọ;+ ó sì gbà mí kúrò lẹ́nu kìnnìún.+ 18 Olúwa máa gbà mí lọ́wọ́ gbogbo iṣẹ́ burúkú, ó sì máa pa mí mọ́ kí n lè wọ ìjọba rẹ̀ ní ọ̀run.+ Òun ni kí ògo jẹ́ tirẹ̀ títí láé àti láéláé. Àmín.

19 Bá mi kí Pírísíkà àti Ákúílà+ àti agbo ilé Ónẹ́sífórù.+

20 Érásítù+ dúró sí Kọ́ríńtì, àmọ́ mo fi Tírófímù+ sílẹ̀ ní Mílétù, ara rẹ̀ ò yá. 21 Sa gbogbo ipá rẹ kí o lè dé kí ìgbà òtútù tó bẹ̀rẹ̀.

Yúbúlọ́sì ní kí n kí ọ, Púdéńsì àti Línúsì àti Kíláúdíà àti gbogbo àwọn ará pẹ̀lú ní kí n kí ọ.

22 Kí Olúwa wà pẹ̀lú ẹ̀mí tí o fi hàn. Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́