ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 8
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ásíríà máa gbé ogun wá (1-8)

        • Maheri-ṣalali-háṣí-básì (1-4)

      • Ẹ má bẹ̀rù⁠—“Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa!” (9-17)

      • Àìsáyà àti àwọn ọmọ rẹ̀ máa jẹ́ àmì (18)

      • Ẹ yíjú sí òfin, kì í ṣe sí àwọn ẹ̀mí èṣù (19-22)

Àìsáyà 8:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “kálámù ẹni kíkú.”

  • *

    Ó ṣeé ṣe kó túmọ̀ sí “Yára Sún Mọ́ Ẹrù Ogun, Tètè Lọ Síbi Ẹrù Ogun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 30:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 12/2016, ojú ìwé 1

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 111-112

Àìsáyà 8:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “jẹ́rìí sí i; kọ̀wé sí i.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 16:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 111-112

Àìsáyà 8:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ìyàwó Àìsáyà.

  • *

    Ní Héb., “sún mọ́ wòlíì obìnrin náà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 8:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2013, ojú ìwé 16-17

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 8, 112

Àìsáyà 8:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 15:29; 16:8, 9; 17:6; Ais 7:16; 17:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 112

Àìsáyà 8:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ṣílóà ni ibi tí omi ń gbà kọjá.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:16; Jer 17:13
  • +Ais 7:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 113-114

Àìsáyà 8:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, odò Yúfírétì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:5; 18:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 113-114

Àìsáyà 8:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Ais 7:14.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 28:19, 20; Ais 7:17, 20; 10:28-32
  • +Ais 7:14; Mt 1:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 113-114, 116

Àìsáyà 8:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ dira.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 32:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 114

Àìsáyà 8:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Lédè Hébérù, Ìmánúẹ́lì túmọ̀ sí “Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa.” Wo Ais 7:14; 8:8.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 20:1; Sm 44:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 114

Àìsáyà 8:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 114-115

Àìsáyà 8:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 114-115

Àìsáyà 8:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 10:3; 22:32
  • +Onw 12:13; Mt 10:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 114-115

Àìsáyà 8:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 21:42, 44; Lk 20:17, 18; Ro 9:31-33; 1Kọ 1:23; 1Pe 2:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2008, ojú ìwé 5

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 115

    Yiyan, ojú ìwé 55

Àìsáyà 8:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 115

Àìsáyà 8:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àkọsílẹ̀ tí wọ́n jẹ́rìí sí.”

  • *

    Tàbí “ìtọ́ni.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 115-116

Àìsáyà 8:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fojú sọ́nà fún.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 33:20
  • +Di 31:16, 17; Mik 3:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 115-116

Àìsáyà 8:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 2:13
  • +Ais 7:14, 16; 8:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 407

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 116

Àìsáyà 8:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 20:6; Di 18:10, 11; Sm 146:4; Onw 9:5, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 29

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 118-121

Àìsáyà 8:20

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àkọsílẹ̀ tí wọ́n fọwọ́ sí.”

  • *

    Ní Héb., “ìmọ́lẹ̀ àárọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 4:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 121-123

Àìsáyà 8:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:15, 48

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 123-124

Àìsáyà 8:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 124

Àwọn míì

Àìsá. 8:1Ais 30:8
Àìsá. 8:22Ọb 16:10
Àìsá. 8:3Ais 8:18
Àìsá. 8:42Ọb 15:29; 16:8, 9; 17:6; Ais 7:16; 17:1
Àìsá. 8:62Ọb 17:16; Jer 17:13
Àìsá. 8:6Ais 7:1
Àìsá. 8:72Ọb 17:5; 18:9
Àìsá. 8:82Kr 28:19, 20; Ais 7:17, 20; 10:28-32
Àìsá. 8:8Ais 7:14; Mt 1:23
Àìsá. 8:92Kr 32:21
Àìsá. 8:10Di 20:1; Sm 44:3
Àìsá. 8:13Le 10:3; 22:32
Àìsá. 8:13Onw 12:13; Mt 10:28
Àìsá. 8:14Mt 21:42, 44; Lk 20:17, 18; Ro 9:31-33; 1Kọ 1:23; 1Pe 2:7, 8
Àìsá. 8:17Sm 33:20
Àìsá. 8:17Di 31:16, 17; Mik 3:4
Àìsá. 8:18Heb 2:13
Àìsá. 8:18Ais 7:14, 16; 8:3, 4
Àìsá. 8:19Le 20:6; Di 18:10, 11; Sm 146:4; Onw 9:5, 10
Àìsá. 8:20Owe 4:19
Àìsá. 8:21Di 28:15, 48
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 8:1-22

Àìsáyà

8 Jèhófà sọ fún mi pé: “Mú wàláà+ ńlá kan, kí o sì fi kálàmù lásán,* kọ ‘Maheri-ṣalali-háṣí-básì’* sára rẹ̀. 2 Mo fẹ́ rí i dájú pé àwọn ẹlẹ́rìí olóòótọ́ fọwọ́ sí i,* ìyẹn àlùfáà Ùráyà+ àti Sekaráyà ọmọ Jeberekáyà.”

3 Lẹ́yìn náà, mo bá wòlíì obìnrin náà* ní àṣepọ̀,* ó sì lóyún, ó wá bí ọmọkùnrin kan.+ Jèhófà wá sọ fún mi pé: “Sọ ọmọ náà ni Maheri-ṣalali-háṣí-básì, 4 torí kí ọmọ náà tó mọ bí wọ́n ṣe ń pe, ‘Bàbá mi!’ àti ‘Ìyá mi!’ wọ́n máa kó àwọn ohun àmúṣọrọ̀ Damásíkù àti ẹrù ogun Samáríà lọ níwájú ọba Ásíríà.”+

5 Jèhófà tún sọ fún mi pé:

 6 “Torí pé àwọn èèyàn yìí ti pa omi Ṣílóà* tó rọra ń ṣàn tì,+

Tí wọ́n sì ń yọ̀ torí Résínì àti ọmọ Remaláyà,+

 7 Torí náà, wò ó! Jèhófà máa mú kí

Ibú omi Odò ńlá* náà ya lù wọ́n,

Ọba Ásíríà+ àti gbogbo ògo rẹ̀.

Ó máa wá sórí gbogbo ibi tí omi rẹ̀ ń ṣàn gbà,

Ó máa kún bo gbogbo bèbè rẹ̀,

 8 Ó sì máa rọ́ gba Júdà kọjá.

Ó máa kún bò ó, ó sì máa gbà á kọjá, ó máa kún dé ọrùn rẹ̀;+

Ìyẹ́ rẹ̀ tó nà jáde máa bo ìbú ilẹ̀ rẹ,

Ìwọ Ìmánúẹ́lì!”*+

 9 Ẹ ṣe wọ́n léṣe, ẹ̀yin èèyàn, àmọ́ a máa fọ́ ẹ̀yin náà sí wẹ́wẹ́.

Ẹ fetí sílẹ̀, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ wá láti apá ibi tó jìnnà ní ayé!

Ẹ múra ogun,* àmọ́ a máa fọ́ yín sí wẹ́wẹ́!+

Ẹ múra ogun, àmọ́ a máa fọ́ yín sí wẹ́wẹ́!

10 Ẹ gbìmọ̀ pọ̀, àmọ́ a máa dà á rú!

Ẹ sọ ohun tó wù yín, àmọ́ kò ní yọrí sí rere,

Torí Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa!*+

11 Pẹ̀lú ọwọ́ agbára rẹ̀ lára mi, ohun tí Jèhófà sọ fún mi nìyí, láti kìlọ̀ fún mi kí n má bàa tẹ̀ lé ọ̀nà àwọn èèyàn yìí:

12 “Tí àwọn èèyàn yìí bá ń pe nǹkan ní ọ̀tẹ̀, ẹ ò gbọ́dọ̀ pè é ní ọ̀tẹ̀!

Ẹ má bẹ̀rù ohun tí wọ́n bẹ̀rù;

Ẹ má ṣe jẹ́ kó kó jìnnìjìnnì bá yín.

13 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ kà sí mímọ́,+

Òun ni Ẹni tó yẹ kí ẹ bẹ̀rù,

Òun sì ni Ẹni tó yẹ kó mú kí ẹ gbọ̀n jìnnìjìnnì.”+

14 Ó máa dà bí ibi mímọ́,

Àmọ́ ó máa dà bí òkúta tí wọ́n á kọ lù

Àti àpáta tó ń múni kọsẹ̀+

Fún ilé Ísírẹ́lì méjèèjì,

Bíi pańpẹ́ àti ìdẹkùn,

Fún àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù.

15 Ọ̀pọ̀ nínú wọn máa kọsẹ̀, wọ́n á ṣubú, wọ́n á sì fọ́;

Wọ́n máa dẹkùn fún wọn, ọwọ́ á sì tẹ̀ wọ́n.

16 Ká ẹ̀rí tó wà lákọsílẹ̀;*

Gbé èdìdì lé òfin* náà láàárín àwọn ọmọ ẹ̀yìn mi!

17 Màá máa dúró de* Jèhófà,+ ẹni tó ń fi ojú rẹ̀ pa mọ́ fún ilé Jékọ́bù,+ màá sì ní ìrètí nínú rẹ̀.

18 Wò ó! Èmi àti àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi+ dà bí àmì+ àti iṣẹ́ ìyanu ní Ísírẹ́lì látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ẹni tó ń gbé lórí Òkè Síónì.

19 Tí wọ́n bá sì sọ fún yín pé: “Ẹ lọ wádìí lọ́wọ́ àwọn abẹ́mìílò tàbí àwọn woṣẹ́woṣẹ́, àwọn tó ń ké ṣíoṣío, tí wọ́n sì ń jẹnu wúyẹ́wúyẹ́,” ṣebí ọwọ́ Ọlọ́run wọn ló yẹ kí àwọn èèyàn ti lọ wádìí? Ṣé ó yẹ kí wọ́n lọ wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ òkú nítorí alààyè?+ 20 Kàkà bẹ́ẹ̀, inú òfin àti ẹ̀rí tó wà ní àkọsílẹ̀* ló yẹ kí wọ́n ti wádìí!

Tí wọn ò bá sọ ohun tó bá ọ̀rọ̀ yìí mu, wọn ò ní ìmọ́lẹ̀.*+ 21 Kálukú máa gba ilẹ̀ náà kọjá, ìyà á jẹ wọ́n, ebi á sì pa wọ́n;+ torí ebi tó ń pa á àti inú tó ń bí i, á máa gégùn-ún fún ọba rẹ̀ àti Ọlọ́run rẹ̀ bó ṣe ń wòkè. 22 Ó máa wá wo ayé, ìdààmú àti òkùnkùn nìkan ló sì máa rí, ìríran bàìbàì àti àkókò tó le, ìṣúdùdù, láìsí ìmọ́lẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́