ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Jòhánù 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Jòhánù

      • Ọ̀rọ̀ ìyè (1-4)

      • Ká máa rìn nínú ìmọ́lẹ̀ (5-7)

      • Ìdí tó fi yẹ ká máa jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wa (8-10)

1 Jòhánù 1:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:4; 6:68

1 Jòhánù 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:3
  • +Jo 21:24; Iṣe 2:32

1 Jòhánù 1:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “lè ṣàjọpín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 15:26, 27; Iṣe 4:20
  • +Jo 17:20, 21

1 Jòhánù 1:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ní ìrẹ́pọ̀ pẹ̀lú rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 1:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    8/1/1991, ojú ìwé 9

1 Jòhánù 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 6:14; Ef 5:8; Tit 1:16; 1Jo 2:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    8/1/1991, ojú ìwé 17-18

1 Jòhánù 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 3:25; Ef 1:7; Heb 9:14; 10:22; Ifi 1:5

1 Jòhánù 1:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:46; Onw 7:20

1 Jòhánù 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 32:5; Owe 28:13; Jem 5:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2020, ojú ìwé 23

Àwọn míì

1 Jòh. 1:1Jo 1:4; 6:68
1 Jòh. 1:2Jo 17:3
1 Jòh. 1:2Jo 21:24; Iṣe 2:32
1 Jòh. 1:3Jo 15:26, 27; Iṣe 4:20
1 Jòh. 1:3Jo 17:20, 21
1 Jòh. 1:5Jem 1:17
1 Jòh. 1:62Kọ 6:14; Ef 5:8; Tit 1:16; 1Jo 2:4
1 Jòh. 1:7Ro 3:25; Ef 1:7; Heb 9:14; 10:22; Ifi 1:5
1 Jòh. 1:81Ọb 8:46; Onw 7:20
1 Jòh. 1:9Sm 32:5; Owe 28:13; Jem 5:16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Jòhánù 1:1-10

Ìwé Kìíní Jòhánù

1 Ohun tó wà láti ìbẹ̀rẹ̀, tí a gbọ́, tí a fi ojú wa rí, tí a kíyè sí, tí a sì fọwọ́ bà, nípa ọ̀rọ̀ ìyè,+ 2 (òótọ́ ni, a fi ìyè náà hàn kedere, a ti rí ìyè àìnípẹ̀kun+ tó wà pẹ̀lú Baba, tí a fi hàn kedere fún wa, à ń jẹ́rìí fún yín nípa rẹ̀,+ a sì ń ròyìn rẹ̀ fún yín), 3 a tún ń sọ àwọn ohun tí a ti gbọ́ tí a sì ti rí fún yín,+ kí ẹ̀yin náà lè ní àjọṣe* pẹ̀lú wa. Àwa àti Baba pẹ̀lú Ọmọ rẹ̀ Jésù Kristi la jọ ní àjọṣe yìí.+ 4 A sì ń kọ àwọn nǹkan yìí kí ayọ̀ wa lè kún rẹ́rẹ́.

5 Ohun tí a gbọ́ látọ̀dọ̀ rẹ̀, tí a sì ń sọ fún yín ni pé: Ọlọ́run jẹ́ ìmọ́lẹ̀,+ kò sì sí òkùnkùn kankan nínú rẹ̀* rárá. 6 Tí a bá sọ pé, “A ní àjọṣe pẹ̀lú rẹ̀,” síbẹ̀ tí à ń rìn nínú òkùnkùn, irọ́ ni à ń pa, a ò sì sọ òótọ́.+ 7 Àmọ́, tí a bá ń rìn nínú ìmọ́lẹ̀ bí òun fúnra rẹ̀ ṣe wà nínú ìmọ́lẹ̀, a ní àjọṣe pẹ̀lú ara wa, ẹ̀jẹ̀ Jésù Ọmọ rẹ̀ sì ń wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀.+

8 Tí a bá sọ pé, “A ò ní ẹ̀ṣẹ̀,” à ń tan ara wa,+ òótọ́ ò sì sí nínú wa. 9 Tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó máa dárí jì wá, ó sì máa wẹ̀ wá mọ́ kúrò nínú gbogbo àìṣòdodo torí olóòótọ́ àti olódodo ni.+ 10 Tí a bá sọ pé, “A ò dẹ́ṣẹ̀,” à ń sọ ọ́ di òpùrọ́, ọ̀rọ̀ rẹ̀ kò sì sí nínú wa.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́