ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Émọ́sì

      • Ìran tó fi hàn pé òpin Ísírẹ́lì ti sún mọ́lé (1-9)

        • Eéṣú (1-3), iná (4-6), okùn ìwọ̀n (7-9)

      • Wọ́n ní kí Émọ́sì má sọ tẹ́lẹ̀ mọ́ (10-17)

Émọ́sì 7:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, ní oṣù January sí February.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2007, ojú ìwé 14

Émọ́sì 7:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “dìde?”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 14:7; Da 9:19
  • +Ais 37:4

Émọ́sì 7:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yí ìpinnu rẹ̀ pa dà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:36; Sm 106:44, 45; Ho 11:8

Émọ́sì 7:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “dìde?”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 32:11
  • +Ais 1:9; Emọ 7:2

Émọ́sì 7:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yí ìpinnu rẹ̀ pa dà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 32:14

Émọ́sì 7:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 84-85

Émọ́sì 7:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 8:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 84-85

Émọ́sì 7:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:25, 31; 13:33
  • +Ho 10:8; Emọ 5:5; 8:14
  • +2Ọb 15:8, 10; Ho 13:16

Émọ́sì 7:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 12:32
  • +2Ọb 14:23
  • +Jer 26:8, 9; Emọ 1:1
  • +Jer 18:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 13

Émọ́sì 7:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 5:5; 6:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 13-14

Émọ́sì 7:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “jẹ búrẹ́dì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 30:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 13

Émọ́sì 7:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 2:12
  • +1Ọb 12:29, 32; 13:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 13

Émọ́sì 7:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ń rẹ́ ọ̀pọ̀tọ́ síkámórè.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 1:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2007, ojú ìwé 16

    11/15/2004, ojú ìwé 10

Émọ́sì 7:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 1:7; Isk 2:3; 2Pe 1:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 11

Émọ́sì 7:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 11:21; Emọ 7:13
  • +Mik 2:6

Émọ́sì 7:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:33; 2Ọb 17:6

Àwọn míì

Émọ́sì 7:2Jer 14:7; Da 9:19
Émọ́sì 7:2Ais 37:4
Émọ́sì 7:3Di 32:36; Sm 106:44, 45; Ho 11:8
Émọ́sì 7:5Ẹk 32:11
Émọ́sì 7:5Ais 1:9; Emọ 7:2
Émọ́sì 7:6Ẹk 32:14
Émọ́sì 7:8Emọ 8:2
Émọ́sì 7:91Ọb 12:25, 31; 13:33
Émọ́sì 7:9Ho 10:8; Emọ 5:5; 8:14
Émọ́sì 7:92Ọb 15:8, 10; Ho 13:16
Émọ́sì 7:101Ọb 12:32
Émọ́sì 7:102Ọb 14:23
Émọ́sì 7:10Jer 26:8, 9; Emọ 1:1
Émọ́sì 7:10Jer 18:18
Émọ́sì 7:11Emọ 5:5; 6:7
Émọ́sì 7:12Ais 30:10
Émọ́sì 7:13Emọ 2:12
Émọ́sì 7:131Ọb 12:29, 32; 13:1
Émọ́sì 7:14Emọ 1:1
Émọ́sì 7:15Jer 1:7; Isk 2:3; 2Pe 1:21
Émọ́sì 7:16Jer 11:21; Emọ 7:13
Émọ́sì 7:16Mik 2:6
Émọ́sì 7:17Le 26:33; 2Ọb 17:6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Émọ́sì 7:1-17

Émọ́sì

7 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ fi hàn mí nìyí: Wò ó! Ó kó ọ̀wọ́ eéṣú jọ ní ìgbà tí irúgbìn àgbìnkẹ́yìn* bẹ̀rẹ̀ sí í dàgbà. Èyí ni irúgbìn àgbìnkẹ́yìn lẹ́yìn tí wọ́n ti gé koríko ọba. 2 Nígbà tí àwọn eéṣú náà jẹ ohun ọ̀gbìn ilẹ̀ náà tán, mo sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, jọ̀wọ́, dárí jì wọ́n!+ Jékọ́bù kò ní okun!+ Báwo ló ṣe máa là á já?”*

3 Nítorí náà, Jèhófà pa èrò rẹ̀ dà.*+ “Kò ní ṣẹlẹ̀,” ni Jèhófà wí.

4 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ fi hàn mí nìyí: Wò ó! Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ lo iná láti fìyà jẹ àwọn èèyàn rẹ̀. Iná náà lá alagbalúgbú omi gbẹ, ó sì jẹ apá kan ilẹ̀ náà run. 5 Mo sì sọ pé: “Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, jọ̀wọ́, má ṣe bẹ́ẹ̀.+ Jékọ́bù kò ní okun!+ Báwo ló ṣe máa là á já?”*

6 Nítorí náà, Jèhófà pa èrò rẹ̀ dà.*+ “Èyí náà kò ní ṣẹlẹ̀,” ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.

7 Ohun tó fi hàn mí nìyí: Wò ó! Jèhófà dúró lórí ògiri kan tí wọ́n fi okùn ìwọ̀n mú tọ́ nígbà tí wọ́n kọ́ ọ, okùn ìwọ̀n kan sì wà ní ọwọ́ rẹ̀. 8 Ìgbà náà ni Jèhófà sọ fún mi pé: “Kí lo rí, Émọ́sì?” Torí náà, mo sọ pé: “Okùn ìwọ̀n.” Jèhófà sì sọ pé: “Wò ó, màá fi okùn ìwọ̀n wọn àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì. Mi ò sì ní forí jì wọ́n mọ́.+ 9 Àwọn ibi gíga Ísákì+ máa di ahoro, àwọn ibùjọsìn Ísírẹ́lì á sì pa run;+ màá fi idà kọ lu ilé Jèróbóámù.”+

10 Amasááyà àlùfáà Bẹ́tẹ́lì+ ránṣẹ́ sí Jèróbóámù+ ọba Ísírẹ́lì pé: “Émọ́sì ń dìtẹ̀ sí ọ láàárín ilé Ísírẹ́lì.+ Àwọn èèyàn ilẹ̀ náà kò lè rí ara gba gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀.+ 11 Nítorí ohun tí Émọ́sì sọ nìyí, ‘Idà ni yóò pa Jèróbóámù, ó sì dájú pé Ísírẹ́lì máa lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀.’”+

12 Ìgbà náà ni Amasááyà sọ fún Émọ́sì pé: “Ìwọ aríran, máa lọ, sá lọ sí ilẹ̀ Júdà, ibẹ̀ ni kí o ti máa wá bí wàá ṣe jẹun,* ibẹ̀ sì ni o ti lè sọ tẹ́lẹ̀.+ 13 Ṣùgbọ́n ìwọ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì mọ́,+ nítorí pé ibùjọsìn ọba ni,+ ilé ìjọba sì ni.”

14 Ìgbà náà ni Émọ́sì dá Amasááyà lóhùn pé: “Wòlíì kọ́ ni mí tẹ́lẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni èmi kì í ṣe ọmọ wòlíì; olùṣọ́ agbo ẹran ni mí,+ mo sì máa ń tọ́jú igi ọ̀pọ̀tọ́ síkámórè.* 15 Àmọ́ Jèhófà sọ fún mi pé kí n má ṣe da agbo ẹran mọ́, Jèhófà sì sọ fún mi pé, ‘Lọ, sọ tẹ́lẹ̀ fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’+ 16 Torí náà, gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà: ‘Ìwọ ń sọ pé, “Ìwọ kò gbọ́dọ̀ sọ tẹ́lẹ̀ lòdì sí Ísírẹ́lì,+ ìwọ kò sì gbọ́dọ̀ kéde ìkìlọ̀+ fún ilé Ísákì.” 17 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Aya rẹ máa di aṣẹ́wó ní ìlú yìí, idà ni yóò pa àwọn ọmọkùnrin rẹ àti àwọn ọmọbìnrin rẹ. Okùn ìdíwọ̀n ni wọ́n á fi pín ilẹ̀ rẹ, orí ilẹ̀ àìmọ́ ni wàá sì kú sí; ó sì dájú pé Ísírẹ́lì máa lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀.”’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́