ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 8
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Émọ́sì

      • Ìran apẹ̀rẹ̀ tí èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn wà nínú rẹ̀ (1-3)

      • Ọlọ́run dẹ́bi fún àwọn aninilára (4-14)

        • Ìyàn tẹ̀mí (11)

Émọ́sì 8:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 4:12; 7:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2007, ojú ìwé 14

    6/15/2007, ojú ìwé 12

Émọ́sì 8:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 10:5; Emọ 5:23
  • +Emọ 6:9, 10

Émọ́sì 8:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 2:6, 7

Émọ́sì 8:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún B14.

  • *

    Wo Àfikún B14.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 10:10
  • +Ẹk 20:8
  • +Le 19:35, 36; Ho 12:7; Mik 6:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 11

Émọ́sì 8:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 25:39; Emọ 2:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 11

Émọ́sì 8:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 33:26; Sm 68:34
  • +Ho 8:13

Émọ́sì 8:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ayé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 4:3
  • +Emọ 9:5

Émọ́sì 8:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 3:6

Émọ́sì 8:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “orin ọ̀fọ̀.”

  • *

    Ní Héb., “aṣọ àpò ìdọ̀họ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 2:11

Émọ́sì 8:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 74:9; Isk 7:26; Mt 4:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2004, ojú ìwé 25

    5/1/2004, ojú ìwé 16-17

    7/1/1998, ojú ìwé 3

Émọ́sì 8:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yíyọ oòrùn.”

Émọ́sì 8:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 8:5; 10:5
  • +1Ọb 12:28-30
  • +Emọ 5:5
  • +2Ọb 18:11; Ho 13:16

Àwọn míì

Émọ́sì 8:2Emọ 4:12; 7:8
Émọ́sì 8:3Ho 10:5; Emọ 5:23
Émọ́sì 8:3Emọ 6:9, 10
Émọ́sì 8:4Emọ 2:6, 7
Émọ́sì 8:5Nọ 10:10
Émọ́sì 8:5Ẹk 20:8
Émọ́sì 8:5Le 19:35, 36; Ho 12:7; Mik 6:10, 11
Émọ́sì 8:6Le 25:39; Emọ 2:6
Émọ́sì 8:7Di 33:26; Sm 68:34
Émọ́sì 8:7Ho 8:13
Émọ́sì 8:8Ho 4:3
Émọ́sì 8:8Emọ 9:5
Émọ́sì 8:9Mik 3:6
Émọ́sì 8:10Ho 2:11
Émọ́sì 8:11Sm 74:9; Isk 7:26; Mt 4:4
Émọ́sì 8:14Ho 8:5; 10:5
Émọ́sì 8:141Ọb 12:28-30
Émọ́sì 8:14Emọ 5:5
Émọ́sì 8:142Ọb 18:11; Ho 13:16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Émọ́sì 8:1-14

Émọ́sì

8 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ fi hàn mí nìyí: Wò ó! Apẹ̀rẹ̀ kan tí èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn wà nínú rẹ̀. 2 Ó wá sọ pé, “Kí lo rí, Émọ́sì?” Mo fèsì pé, “Apẹ̀rẹ̀ tí èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn wà nínú rẹ̀.” Jèhófà wá sọ fún mi pé: “Òpin ti dé bá àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì. Èmi kò ní forí jì wọ́n mọ́.+ 3 ‘Àwọn orin tẹ́ńpìlì máa di igbe ẹkún ní ọjọ́ yẹn,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. ‘Òkú á sì sùn lọ bẹẹrẹ níbi gbogbo.+ Dákẹ́!’

 4 Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ni àwọn tálákà lára

Tí ẹ sì ń pa àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ ilẹ̀ yìí,+

 5 Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sọ pé, ‘Ìgbà wo ni àjọ̀dún òṣùpá tuntun máa parí,+ ká lè ta àwọn hóró ọkà wa,

Àti ìparí Sábáàtì,+ ká lè gbé hóró ọkà lọ fún títà?

Ká lè sọ òṣùwọ̀n eéfà* di kékeré

Kí a sì sọ ṣékélì* di ńlá,

Kí a dọ́gbọ́n sí àwọn òṣùwọ̀n wa, kí a lè fi tanni jẹ;+

 6 Kí a lè fi fàdákà ra àwọn aláìní

Kí a sì fi owó bàtà ẹsẹ̀ méjì ra àwọn tálákà,+

Kí a sì lè ta èyí tí kò dáa lára ọkà.’

 7 Jèhófà ti fi Ògo Jékọ́bù+ búra,

‘Mi ò ní gbàgbé gbogbo ohun tí wọ́n ṣe.+

 8 Nítorí èyí, ilẹ̀ náà* á mì tìtì,

Gbogbo àwọn tó ń gbé orí rẹ̀ á sì ṣọ̀fọ̀.+

Ǹjẹ́ kò ní ru sókè bí odò Náílì,

Kí ó sì bì síwá sẹ́yìn, kí ó wá rọlẹ̀ bí odò Náílì Íjíbítì?’+

 9 ‘Ní ọjọ́ yẹn,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí,

‘Màá mú kí oòrùn wọ̀ ní ọ̀sán gangan,

Màá sì mú kí ilẹ̀ náà ṣókùnkùn ní ojúmọmọ.+

10 Màá sọ àwọn àjọyọ̀ yín di ọ̀fọ̀+

Gbogbo orin yín á sì di orin arò.*

Màá sán aṣọ ọ̀fọ̀* mọ́ gbogbo ìbàdí, màá sì mú gbogbo orí pá;

Màá ṣe é bí ìgbà téèyàn ń ṣọ̀fọ̀ nítorí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo,

Màá sì mú kí ìgbẹ̀yìn rẹ̀ dà bí ọjọ́ tó korò.’

11 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí,

‘Nígbà tí màá rán ìyàn sí ilẹ̀ náà,

Kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí ti omi,

Bí kò ṣe ti gbígbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà.+

12 Wọ́n á ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́ láti òkun dé òkun

Láti àríwá sí ìlà oòrùn.*

Wọ́n á máa wá ọ̀rọ̀ Jèhófà káàkiri, ṣùgbọ́n wọn ò ní rí i.

13 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn arẹwà wúńdíá máa dá kú,

Àti àwọn ọ̀dọ́kùnrin pàápàá, nítorí òùngbẹ náà;

14 Àwọn tó ń fi ẹ̀ṣẹ̀ Samáríà+ búra, tí wọ́n sì ń sọ pé,

“Bí ọlọ́run rẹ ti wà láàyè, ìwọ Dánì!”+

Àti “Bí ọ̀nà Bíá-ṣébà+ ti ń bẹ!”

Wọ́n á ṣubú, wọn ò sì ní dìde mọ́.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́